Yusuf Mugu
Ìrísí
Yusuf Mugu | |
---|---|
Member of the Kaduna State House of Assembly | |
Constituency | Kaura Constituency |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Kaduna State, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Peoples Democratic Party (PDP) |
Occupation | Politician |
Yusuf Mugu jẹ olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà to n se aṣojú fun àgbègbè Kaura ni ile ìgbìmọ̀ asofin ìpínlẹ̀ Kaduna . [1] [2] [3]