Zara Mohamed
Zara Mohammed Abdulmajid (bíi ni ọjọ́ kẹẹdọgbọn oṣù keje ọdún 1995[1]) jẹ́ òṣèré, mọ́dẹ́lì àti oníṣòwò lórílẹ̀-èdè Uganda.
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Iman sí ìlú Mogadishu ní Somalia[2]. Iman jẹ́ ọmọ Mariam àti Mohammed Abdulmajid.[3] Bàbá rẹ̀ jẹ́ àmbásẹ́dọ̀ Somalia fún orílè-èdè Saudi Arabia[4], ìyá rẹ sí jẹ́ dókítà[5]. Ọmọ márùn-ún sí ni àwọn òbí rẹ bí.[6] Nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́rin, ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ lórílẹ̀-èdè Egypt.[7] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Nairobi ní ọdún 1975 láti kẹ́kọ̀ọ́ òṣèlú.[8][9]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ mọ́dẹ́lì nígbà tí ó wà ní ilé ẹ̀kọ́ gíga.[10] Ó ti ṣe mọ́dẹ́lì fún Halston, Gianni Versace, Calvin Klein, Issey Miyake and Donna Karan.[11][12][13][14] àti Tess Management[15]. Iman bẹ̀rẹ̀ sí ní ta jìgì ojú fún àwọn obìnrin ní ọdún 1994[16]. Ní ọdún 2012, ó fi Ayaan àti Idyl Mohalim fi ṣe àmbásẹ́dọ̀ fún ilé iṣẹ́ rẹ̀.[17] Iman kópa nínú eré Star Trek VI: The Undiscovered Country ní ọdún 1991 gẹ́gẹ́ bí Martia[18]. Ní ọdún 1998, ó kó ipa Marie Babineaux nínú eré In the Heat of the Night[19]. Ní oṣù kọkànlá ọdún 2010, òun àti Isaac Mizrahi jọ ṣe atọ́kun fún apá kejì ètò The Fashion Show.[20] Lára àwọn eré tí Iman tí kópa nínú wọn ni The Human Factor, Out of Africa, Surrender, Heart of Darkness[21], No Way Out, Lies of the Twins, Star Trek, The Linguini Incident àti Exit to Eden.[22][23] Ó jẹ́ àmbásẹ́dọ̀ fún Save the Children[24][25][26]. Ní ọjọ́ keje oṣù kẹfà ọdún 2010, ó gba àmì ẹ̀yẹ Fashion Icon láti ọ̀dọ̀ Council of Fashion Designers of America.[27]
Ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Iman jẹ́ Mùsùlùmí[28], ó sì lè sọ èdè márùn-ún: Somalia, Lárúbáwá, Italian, French àti Gẹ̀ẹ́sì[29]. Iman kọ́kọ́ fẹ́ Hassan nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún méjìdínlógún.[30][31] Ní ọdún 1977, ó fẹ́ Warren Beatty.[32] Ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Spencer Haywood ní ọdún náà, wọn sì bí ọmọbìnrin kan ní ọdún 1978. Ìgbéyàwó náà túká ní oṣù kejì ọdún 1987.[33] Ní ọdún 1992, ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú David Bowie[34][35], wọn sì bí ọmọ kan ní ọdún 2000.[36][37] Bowie kú ni ọjọ́ kẹwàá oṣù kìíní ọdún 2016.[38]
Àwọn Ìtọ́kàsi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Iman, Peter Hill Beard, David Bowie, I Am Iman (Universe Publishing, 2001), p. 15.
- ↑ Hendrikse, Wim (2013). David Bowie – The Man Who Changed the World. New Generation Publishing. pp. 410–411. ISBN 978-0755250530. https://www.google.com/books?id=gq9Vp45cGx4C&source=gbs_navlinks_s. Retrieved 18 January 2016.
- ↑ Iman, Peter Hill Beard, David Bowie, I Am Iman, p. 11.
- ↑ Supermodel Iman is Ottawa bound for TV show Archived 7 November 2012 at the Wayback Machine.. Canada.com (25 June 2008). Retrieved 9 May 2012.
- ↑ Women of Achievement – Iman. Thelizlibrary.org. Retrieved 9 May 2012.
- ↑ Iman, Peter Hill Beard, David Bowie, I Am Iman, p. 17.
- ↑ "Archived copy". Archived from the original on 7 June 2010. Retrieved 10 March 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help). New York Times (6 June 2010) - ↑ Leslie Halliwell, John Walker (2001). Halliwell's Who's who in the Movies. HarperCollinsEntertainment. p. 225. ISBN 0002572141. https://www.google.com/books?id=ZZgrAQAAMAAJ. Retrieved 18 January 2016.
- ↑ Mukhtar, Mohamed Haji (2003). Historical Dictionary of Somalia. Scarecrow Press. p. 113. ISBN 0810866048. https://www.google.com/books?id=DPwOsOcNy5YC&pg=PA113. Retrieved 28 February 2018.
- ↑ Iman – Profiles – Project Runway Canada Archived 27 May 2010 at the Wayback Machine.. Slice.ca. Retrieved 9 May 2012.
- ↑ "Archived copy". Archived from the original on 7 June 2010. Retrieved 10 March 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help). New York Times (6 June 2010) - ↑ INTERNATIONAL SUPERMODEL IMAN TO HOST PROJECT RUNWAY CANADA Archived 13 July 2011 at the Wayback Machine.
- ↑ New Chapters for Iman. Los Angeles Times. (24 December 2001). Retrieved 9 May 2012.
- ↑ Beauty Icon: Iman. Style.com. Retrieved 9 May 2012.
- ↑ Iman Portfolio Archived 26 May 2010 at the Wayback Machine.. Tess Management. Retrieved 9 May 2012.
- ↑ Working Woman, Volume 20, Issues 1–6. MacDonald Communications Corporation. 1995. p. 67. https://www.google.com.au/books?id=EfwfAQAAIAAJ&q=%22Iman+is+outselling+Flori+Roberts+and+Fashion+Fair,+the+two+stalwarts+of+the+ethnic-+cosmetics+market.%22&dq=%22Iman+is+outselling+Flori+Roberts+and+Fashion+Fair,+the+two+stalwarts+of+the+ethnic-+cosmetics+market.%22&hl=en&sa=X&ved=0ahUKEwj0s-WMrcTaAhVJO7wKHXHwDw8Q6AEIJzAA. Retrieved 18 April 2018.
- ↑ PAPERMAG. "Designers and Twins Ayaan and Idyl Mohallim Find Fans of Their Line Mataano the World Over.". Retrieved 4 August 2016.
- ↑ "28 Surprising Star Trek Guest Stars : Iman, Star Trek VI: The Undiscovered Country | TV Guide". TV Guide. Retrieved 10 June 2019.
- ↑ "Iman". IMDb. Retrieved 4 August 2016.
- ↑ Sneak peek : 'The Fashion Show: Ultimate Collection' Archived 23 July 2011 at the Wayback Machine.. Denver.metromix.com. Retrieved 9 May 2012.
- ↑ Voyeurism: (fin de siecle), Volume 2, Issue 2 of Felix (New York, N.Y.). The Standby Program. 2000. p. 89. https://www.google.com/books?id=sX00AQAAIAAJ. Retrieved 8 June 2018.
- ↑ John C. Brasfield Pub. Corp. (1992). Architectural Digest 49 (7–9): 200.
- ↑ "Omikron: The Nomad Soul". Allgames. Archived from the original on 10 December 2014. Retrieved 4 August 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Five Seeds of Hope for Somalia". HuffPost. 13 October 2011. http://www.huffingtonpost.com/iman/five-seeds-of-hope-for-somalia_b_926155.html?ncid=edlinkusaolp00000009.
- ↑ "Exclusive: An Intimate Interview with Supermodel and Activist Iman".
- ↑ Meldrum, Andrew (9 May 2004). "Iman cuts De Beers links in ethics row". The Guardian (London). https://www.theguardian.com/world/2004/may/09/humanrights.andrewmeldrum. Retrieved 15 August 2011.
- ↑ Dodes, Rachel (9 June 2010). Kors, Jacobs, Iman Take Home Fashion Awards. The Wall Street Journal. Retrieved 9 May 2012.
- ↑ Marshall Cavendish Reference (2011). Illustrated Dictionary of the Muslim World. Marshall Cavendish. p. 108. ISBN 978-0761479291. https://archive.org/details/illustrateddicti0000unse/page/108. Retrieved 27 June 2016.
- ↑ "The World of Work" (PDF). Archived from the original (PDF) on 10 February 2015. Retrieved 10 February 2015.
- ↑ Iman, Peter Hill Beard, David Bowie (2001). I Am Iman. Universe Pub.. p. 54. ISBN 0789306336.
- ↑ Newsweek, Volume 86. Newsweek, Incorporated. 1975. p. 46. https://www.google.com/books?id=uaoeAQAAMAAJ. Retrieved 18 January 2016.
- ↑ Krivoshey, Bethsabée (5 November 2015). "Tableau de chasse – Les célèbres conquêtes de Warren Beatty – Iman". Vanity Fair. Archived from the original on 17 August 2017. https://web.archive.org/web/20170817235412/http://www.vanityfair.fr/people/legendes/diaporama/les-celebres-conquetes-de-warren-beatty/23464#iman. Retrieved 25 April 2016.
- ↑ "Spenser Haywood timeline". The Seattle Times. 25 February 2007. http://www.seattletimes.com/sports/spenser-haywood-timeline/. Retrieved 24 April 2016.
- ↑ Sandle, Paul; Faulconbridge, Guy (11 January 2016). "David Bowie dies after 18-month battle with cancer". Reuters. https://www.reuters.com/article/us-people-bowie-death-idUSKCN0UP0KD20160111. Retrieved 11 January 2016.
- ↑ Pegg, Nicholas (2006). The Complete David Bowie. Reynolds & Hearn. pp. 238. ISBN 1905287151.
- ↑ FIRST LOOK: The News in Brief, August 15, 2000. E!.com (15 August 2000). Retrieved 9 May 2012.
- ↑ "'He still ties my shoes for me': Iman reveals how David Bowie makes her feel special". Fashion Model Directory. 25 December 2010. Retrieved 9 May 2012.
- ↑ "'The struggle is real, but so is God': See Iman's poignant David Bowie tribute". Today. 11 January 2016. http://www.today.com/popculture/struggle-real-so-god-see-iman-s-poignant-david-bowie-t66481. Retrieved 15 January 2016.