Zemzem Ahmed
Ìrísí
Ahmed at the 2014 Paris Marathon | |
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Orúkọ kíkúnrẹ́rẹ́ | Zemzem Ahmed Deko |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Ethiopia |
Ọjọ́ìbí | 27 Oṣù Kejìlá 1984 Asella, Ethiopia |
Height | 1.70 m (5 ft 7 in) |
Weight | 53 kg (117 lb) |
Sport | |
Erẹ́ìdárayá | Athletics (sport) |
Event(s) | Steeplechase |
Club | Banks SC (ETH) |
Zemzem Ahmed Deko ni a bini ọjọ kẹta dinlọgbọn, óṣu December ni ọdun 1984 ni ilu Asella jẹ elere sisa ti Steeplechase ati ti óju ọna ti órilẹ ede Ethiopia. Arabinrin naa jẹ ọkan lara awọn elere sisa ti steeplechase to pegede julọ ni ilẹ Ethiopia[1].
Àṣèyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Zemzem ṣoju Ethiopia ninu Olympics ti Summer to waye ni Beijing ni ọdun 2008 to si kopa ni steeplechase ti awọn óbinrin ti ẹgbẹrun mẹta Metre[2]. Ni ọdun 2009, Arabinrin naa kopa ninu idije agbaye ti ere sisa to si gbe ipo kẹwa ninu steeplechase pẹlu ere ti iṣẹju 9:22.64. Ni ọdun 2012, Arabinrin naa kopa ninu Marathon ti Frankfurt nibi to ti gbe ipo kẹfa pẹlu wakati 2:27:12[3].