Àwo Àlẹ̀mọ́lẹ̀
Ìrísí
Awo Àlẹ̀mọ́lẹ̀ni ohun tí wọ́n fi àwọn èlò bí sẹ̀rámíìkì, òkúta láti ara àpáta, irin, amọ̀ tàbí díígí ṣe. [1]
Lílò rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n ma ń lo àwo àlẹ̀mọ́lẹ̀ fún ṣíse ilẹ̀, ara ilé tàbí òrùlé ṣe lọ́jọ̀. [2]
Ìrísí rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwo àlẹ̀mọ́lẹ̀ ma ní igun mẹ́rin, mẹ́ta, tàbí kí ó rí róbótó nígbà tí wọ́n bá ṣeé tán. Ìrísí rẹ̀ dá lórí bí olùpèsè rẹ̀ bá ṣe fẹ́ kí ó rí. Pàtàkì àwo Alẹ̀mọ́lẹ̀ ni kí ó ma san gbinrin. Dídán yí ni yóò mú kí ẹwà ibi tí wọ́n bá lẹ̀ẹ́ mọ́ ó yọ. [3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Tile". The Tile Shop. Retrieved 2020-02-11.
- ↑ "Bathroom Tiles - Wall & Floor Tiles". Fired Earth. Retrieved 2020-02-11.
- ↑ "Wall Tiles & Wall Tiling for Kitchens and Bathrooms, Tiles UK". Tons of Tiles UK. 2019-07-17. Retrieved 2020-02-11.