Èdè Sindhi
Ìrísí
Sindhi | ||||||
---|---|---|---|---|---|---|
سنڌي , सिन्धी ,Sindhī | ||||||
Sísọ ní | Pakistan, India. Also Hong Kong, Oman, Philippines, Singapore, UAE, UK, USA, Afghanistan | |||||
Agbègbè | South Asia | |||||
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | 21 million[1] | |||||
Èdè ìbátan | Indo-European
| |||||
Sístẹ́mù ìkọ | Arabic, Devanagari, Laṇḍā | |||||
Lílò bíi oníbiṣẹ́ | ||||||
Èdè oníbiṣẹ́ ní | Sindh, Pakistan India | |||||
Àkóso lọ́wọ́ | Sindhi Language Authority (Pakistan) | |||||
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | ||||||
ISO 639-1 | sd | |||||
ISO 639-2 | snd | |||||
ISO 639-3 | snd | |||||
|
Ede Sindhi (Sindhi: سنڌي, Urdu: سندھی,Devanagari script: सिन्धी, Sindhī) je ede ni agbegbe Sindh ni Pakistan loni. Iye awon eniyan to un so ni Pakistan je 24,410,910, bakanna ni India iye awon to n so je 2,535,485.[1] O je ede iketa ni Pakistan, ati ede ibise ni Sindh ni Pakistan. O tun je ede ibise ni India. Kadi idanimo ti ijoba ile Pakistan un te jade je ni ede meji nikan pere, Sindhi ati Urdu.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Sindhi language at Ethnologue