Èdè Tiv
Ìrísí
Tiv | |
---|---|
Sísọ ní | Gúúsù-Ìlàòrùn Nàìjíríà |
Ọjọ́ ìdásílẹ̀ | 1991 |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | 2,200,000 |
Èdè ìbátan | |
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-3 | tiv |
Tiv jẹ́ èdè tí wón so ní Nàìjíríà (ní àwọn Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé, Plateau, Tàràbà, Násáráwá àti Agbègbè Olúìlú Ìjọba Àpapọ̀ Abùjá) àti ní orílẹ̀-èdè Cameroon. Àwọn ènìyàn tí ó lé ní milionu márùn-ún ni ó ń sọ èdè náà. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn tí wón ń so èdè TIV wá láti Ìpínlẹ̀ Benue.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- R.C.Abraham, A Dictionary of the Tiv Language, Government of Nigeria 1940, republished by Gregg Press Ltd., Farnborough, Hants., England 1968. ISBN 0576116157
- Map of Tiv (Munshi) language from the LL-Map project
- Information on Tiv language from the MultiTree project
- Ethnologue report
- More info on Tiv
- Ate-u-Tiv Social Network Archived 2011-07-07 at the Wayback Machine.
- PanAfrican L10n page on Tiv