Babayo Garba Gamawa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Babayo Garba Gamawa
aṣojú Àríwá Ìpínlẹ̀ Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
Ọjọ́ ọ̀kàndínlọ́gbọ̀ Oṣù karún Ọdún 2011
ConstituencyÀríwá Bauchi
Àwọn àlàyé onítòhún
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (PDP)
OccupationOníṣòwò
ProfessionOlóṣèlú

Babayo Garba Gamawa jẹ́ oníṣòwò àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Àríwá Ìpínlẹ̀ Bauchi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2][3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Babayo Garba Gamawa Homepage". Senator's Homepage. 
  2. Abubakar, Muhammad. "Nigeria: Two Deputy Governors in Bauchi". AllAfrica. Retrieved 17 May 2012. 
  3. Micheal, Ishola (1 July 2010). "Bauchi: A case of two sitting deputy govs". http://tribune.com.ng/index.php/politics/7592-bauchi-a-case-of-two-sitting-deputy-govs. Retrieved 17 May 2012.