John Maynard Keynes

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
John Maynard Keynes
Keynesian economics
Born(1883-06-05)5 Oṣù Kẹfà 1883
Cambridge, England
Died21 April 1946(1946-04-21) (ọmọ ọdún 62)
Firle, East Sussex, England
NationalityBritish
FieldPolitical economy, probability
Alma materKing's College, Cambridge
OpposedMarx · Hayek · Walras · Marshall · Pigou
InfluencesSmith · Ricardo · Hume · Mill · Malthus · Gesell · Moore · Marshall · Wicksell · Robertson
InfluencedWhitaker · Lynch · Kalecki · Kuznets · Samuelson · Hicks · Shackle · Vickrey · Galbraith · Minsky · Shiller · Stiglitz · Krugman · Roubini
ContributionsMacroeconomics, Keynesian Economics, Liquidity preference, Spending multiplier, Aggregate Demand-Aggregate Supply model

John Maynard Keynes, 1st Baron Keynes (play /ˈknz/ KAYN-z; 5 June 1883 – 21 April 1946), CB, je ara Britani aseoro-okowo ti eroinu re ko ipa pataki lori irojinle ati imuse oro-okowotitobi odeoni, ati awon iselu oro-okowo awon ijoba. O se atunse gidigidi ise tele lori awon ohun toun fa iyipo osowo, o si polongo fun ilo awon eto isenawo ati oro owo lati satunse ipa buburu awon economic ifaseyin oro-okowo ati itelole oro-okowo. Awon eroinu re ni won di pepe fun ile-eko ero toun je oro-okowo Keynes, ati iru awon to wa lati inu re.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]