Segun Arinze

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Segun Arinze
Ọjọ́ìbíSegun Padonou Aina
1965 (ọmọ ọdún 58–59)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaObafemi Awolowo University
Iṣẹ́Actor/Producer/PR/Talkshow host

Segun ArinzeYo-Segun Arinze.ogg Listen (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Segun Padonou Aina,[1] tí wọ́n bí ní ọdún 1965) jẹ́ òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdẹ̀ Nàìjíríà[2] àti òǹkọrin.[3][4][5][6][7]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Òun ni àkọ́bí láàárín àwọn ọmọ méje tí Lydia Padonu bí.[8] ÌlúBadagry, ní Ìpínlẹ̀ Èkó ló ti wá. Ilé-ìwé Victory College of Commerce ní Ilorin ló lọ, kí ó tó wá lọ sí Taba Commercial College ní Ìpínlẹ̀ Kàdúná láti parí ẹ̀kọ́ girama rẹ̀. Ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa Dramatic Arts ní Obafemi Awolowo University. Ó gba orúkọ ìnagijẹ Black Arrow làtàrí ẹ̀dá-ìtàn tó ṣe nínú eré ọdún 1996 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "Silent Night" èyí tí Chico Ejiro gbé jáde.[9][10]

Ó fẹ́ òṣèrébìnrin ẹgbẹ́ rẹ̀, tórúkọ rè ń jẹ́ Anne Njemanze, àmọ́ ìgbéyàwọ́ yìí ò pẹ́ rárá.[11] Tọkọ-taya náà bímọ obìnrin kan, tí wọ́n sọ ní Renny Morenike, tí wọ́n bí ní ọjọ́ 10, oṣụ̀ karùn-ún.[12]

Iṣẹ́ tó yàn láàyò[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Segun Arinze bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tó yàn láàyò gẹ́gẹ́ bí i akọrin àti òṣèré. Orin kíkọ ló kọ́kọ́ gbe síta gbangba, lẹ́yìn ṣàbéjáde orin kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Dream.[13] Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní kópa nínú fíìmù àgbéléwò ní ìlú Ilorin. Yàtọ̀ sí iṣé òṣèré tó yàn, Segun tún jẹ́ akọ́nimọ̀ọ́ṣe-fíìmù, tó sì ń ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú African international film festival, tó sì ń fún àwọn ìran òṣèré tó ń bọ̀ lẹ́yìn mu nínú omi ìmọ̀ rẹ̀.[14][15][16]

Àṣàyàn fíìmù rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Across the Niger
  • Silent Night
  • Chronicles (pẹ̀lú Onyeka Onwenu àti Victor Osuagwu)
  • Family on Fire (2011)
  • A Place in the Stars (2014)
  • Invasion 1897 (2014)[17][18]
  • Deepest Cut (2018) - pẹ̀lú Majid Michel àti Zach Orji
  • The Island Movie (2018)[19]
  • Gold Statue (2019)
  • Òlòtūré (2019)
  • She Is (2019)
  • Who's the Boss (2020)
  • Blood Sisters (2022)
  • Blogger's Wife (2017)
  • Highway to the Grave (1999)

Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Year Award ceremony Category Film Result Ref
2017 Best of Nollywood Awards Best Supporting Actor –English Tatu Wọ́n pèé [20]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Segun Arinze's debut album". punchng.com. Archived from the original on 14 August 2014. Retrieved 13 August 2014. 
  2. Aileru, Islamiat (1 November 2021). "'Something big is coming' Segun Arinze links up with Pete Edochie and Kanayo O Kanayo for a new project". Kemi Filani News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 14 March 2022. 
  3. "'The Heroes' unites Segun Arinze, Ifeanyi Onyeabor". vanguardngr.com. Retrieved 13 August 2014. 
  4. "Segun Arinze, Onyeabor lead search for cultural heroes". punchng.com. Archived from the original on 14 August 2014. Retrieved 13 August 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "Nollywood Star Actor, Segun Arinze Weds Lover". modernghana.com. Retrieved 13 August 2014. 
  6. "Segun Arinze and Ann Njemanze with Emeka Ike – Exclusive". thediasporanstaronline.com. Retrieved 13 August 2014. 
  7. "AGN: Ejike Asiegbu, Segun Arinze back Ibinabo for re-election". vanguardngr.com. Retrieved 13 August 2014. 
  8. "Segun Arinze Aina Padonu: Nollywood's timeless star". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 12 August 2017. Retrieved 26 March 2021. 
  9. "How Chico Ejiro inspired my bald look – Segun Arinze". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 February 2021. Retrieved 26 March 2021. 
  10. "Sequel of Segun Arinze's 'Black Arrow' underway". thenationonlineng.net. https://thenationonlineng.net/sequel-segun-arinzes-black-arrow-underway/. 
  11. "Nollywood actress, Anne Njemanze celebrates her daughter who turns a year older today". bioreports. Retrieved 13 October 2020. 
  12. "Segun Arinze's Daughter Renny, Accuses him of Sending her 'fake' Happy Birthday Wishes on Instagram". motherhoodinstyle. Retrieved 11 October 2020. 
  13. "Segun Arinze Aina Padonu: Nollywood's timeless star". m.guardian.ng. Retrieved 26 March 2021. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  14. "nigeria.shafaqna.com". Nigeria News (News Reader) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2 December 2019. 
  15. "Segun Arinze The man once known as Nollywood's bad boy". www.pulse.ng. Retrieved 2 December 2019. 
  16. Nigeria, Ckn. "My Dad Wanted Me To Be A Lawyer..Segun Arinze". Retrieved 2 December 2019. 
  17. "Lancelot Imasuen's Invasion 1897 hits cinemas Dec 5". The Sun. Our Reporter. Retrieved 16 November 2014. 
  18. "'Invasion 1897' Lancelot Imaseun's movie set for cinema release". Pulse Nigeria. Chidumga Izuzu. Retrieved 26 November 2014. 
  19. "the island ( 2018)". nlist.ng. https://nlist.ng/title/the-island-1107/. 
  20. "BON Awards 2017: Kannywood’s Ali Nuhu receives Special Recognition Award". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 23 November 2017. Retrieved 7 October 2021.