Viola Onwuliri

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Prof. Viola Adaku Onwuliri
Pro-Chancellor, Nigerian Maritime University (NMU)
In office
2015 – Present
Minister of Education, State-1
In office
2014–2015
AsíwájúEzenwo Nyesom Wike
Arọ́pòA. Anwukah
Minister of Foreign Affairs
In office
2013–2014
AsíwájúOlugbenga Ashiru
Arọ́pòAminu Bashir Wali
Minister of Foreign Affairs, State-1
In office
2011–2013
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí18 June 1956
Mbaise
Ọmọorílẹ̀-èdèNigeria
(Àwọn) olólùfẹ́Prof. Celestine Elihe Onwuliri (m. 14Jul1978; d. 3Jun2012)
Àwọn ọmọ5 (Ije,Kenn,eMeka,Dan,Toch)
Alma materUniversity of Nigeria, Nsukka
University of Jos
Howard University
Harvard University

Viola Adaku Onwuliri tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù Kẹfà ọdún 1956, jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ìmọ̀ Biochemistry àti olóṣèlú tí ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí aṣojú fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sí ile.̀ òkèrè

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Viola jẹ̣́ àkọ́bí nínú àwọn ọmọ Ọba Eze Cletus àti Ugoeze Dorathy Oparaoji ti ìlú Amuzi, ní ìjọba ìbílẹ̀ Ahiazu Mbaise, Ìpínlẹ̀ Imo. O je ọmọ bíbí ìlú Ahiazu MbaiseÌpínlẹ̀ Imo , ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n bí Viola ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 1956. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Owerri Girls' Secondary School ṣáájú kí ó tó lọ sí ilẹ̀-èkó gíga Yunifásitì Nigeria, Nsukka níbi tí ó ti kàwé gboyè àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ Biochemistry. Ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásitì Jos níbi tí ó ti gbà ìwé ẹ̀rí PGCE, àti MSc nínú ìmọ̀ ''Applied Organic Chemistry'' tí ó sì gba oyè Ọ̀mọ̀wé nínú ìmọ̀ ''Molecular Biochemistry''. Ó sì tún lọ kàwé ní ilé-ẹ̀kọ́ Howard University àti Harvard School of Public Health ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà .

Hillary Clinton welcomed by Foreign ministers Olugbenga Ashiru and Viola Onwuliri in 2012

Viola padà sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, níbi tí ó ti gbaṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùrànlọ́wọ́ olùkọ́ fásitì ní ọdún 1981. Ní ọdún 2004, ó di ọjọgbọn nínú Biochemistry ni University of Jos.[citation needed] Lásìkò yí, òun ati ọkọ rẹ, Celestine Onwuliri, ti bímọ márùn ún.

Ní ọdún 2004, Viola di obìnrin àkọ́kọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti obìnrin àkọ́kọ́ tí wọ́n dìbò yàn sínú International AIDS Society (IAS) tí ó wà ní Geneva, tí ó sì ṣojú fún ilẹ̀ Áfíríkà láti ọdún 2004 sí 2008, wọ́n sì tún yàn án sìpò fún ọdún mẹ́rin mìíràn.

Ní ọdún 2011, Ó díje dupò gómìnà Ìpínlẹ̀ Ímò pelu gomina Ikedi Ohakim, Leyin ti won padanu ninu idibo naa, gomina Rochas Okorocha ti o wole ninu idibo naa yan Viola fun ipo komisona, amo Viola ko lati gba ipo naa ti o si ya gbogbo eniyan lenu.

Lẹ́ỵ̀in ìgbà díẹ̀, Viola di Mínísítà with her own party and she made the news when on thursday 17 October 2013 she led the Nigeria delegation to win the seat of the United Nations Security Council (UNSC) in an unprecedented Global election just two years after leaving the council which was an uncommon feat that was expected to be achieved much later in around 10 years time.


She was also in the spotlight when she called for Libya's ruler, Moammar Gadhafi, to resign stating that the Libyan rebel council best represented the Libyan people. The same month as Foreign Minister, she visited the scene of the Abuja United Nations bombing which killed over 20 people. She was quoted saying: "This is not an attack on Nigeria but on the global community. An attack on the world."[1] Disaster struck with the Dana Air Flight 992 plane crash in June 2012 that killed her husband Celestine Onwuliri and over 150 others. He had been the Vice-Chancellor of the Federal University of Technology Owerri (FUTO). As the wife of the Vice Chancellor of FUTO and the Founder and President of the FUTO Women's Association (FUTOWA) (2006-2011), she played a critical role in job creation, the development of FUTO through FUTOWA including the creation of childcare facilities for staff and students, the establishment of the child development centre and the elevation of the status of women in FUTO. She caused a stir in late 2013 as Foreign Minister when she requested that the Imo Governor at the time give an expenditure account of monies in form of allocations from the Federal Government he received on behalf of Imo State, including Sure-P Fund, Erosion control, Flood money, LGA Allocations, NDDC allocations and other Sundry monies As Foreign Affairs Minister she worked to re-establish and improve relationships with Nigerians in the Diaspora, as first step towards creating conducive environment to attract Diaspora Nigerians participation in accomplishing the Agenda of the President and to attract increased Foreign Direct Investment and Foreign Direct Remittances which rose to 8billion dollars and 21 billion dollars respectively during her tenure, working to promote respect of and improve the treatment of Nigerians in the diaspora; and she became the first seating Nigerian Minister to be officially hosted at the esteemed historically Black University, Howard University. As Nigeria's Minister of Foreign Affairs she served from 11 July 2011- 22 October 2014 which included serving as the State-1 Minister and then the Supervising Minister of the Ministry of Foreign Affairs between 2013 and 2014 before being moved to the Education Ministry as its State-1 Minister.

Ní ọdún 2013, o di alaga fun GlobalPOWER Women Network Africa. Leyin odun yi, o gba ami-eye 'European Union Honorary Platinum Leadership Award Archived 2018-07-08 at the Wayback Machine. ninu oselu ni ojo kejidinlogbo osu Kokanla odun 2013 ni agbegbe Stockholm, ni orile-ede Swídìn.

Onwuliri di alaga obinrin ni inu egbe SWAAN ti o si sise bi ''Principal Investigator and Project Director'' pelu ajosepo pelu ile-ise ''Bill and Melinda Gates Foundation''. Aare Goodluck Jonathan fi Onwuliri se Minisita fun ''Minister of State for Education'' ni inu osu Kewaa odun 2014 nigba ti Ezenwo Nyesom Wike kowe fi ipo sile.

Ẹ tún lè wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Minister of Foreign Affairs (Nigeria)

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]