Jump to content

Iyabo Ojo: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
New Page
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
 
Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù
Ìlà 1: Ìlà 1:
Ìyábọ́ Alice Òjó (tí a bí ní Ọjọ́ kọnkànlélógún oṣù Kejìlá ọdún 1977)jẹ́ òṣèrébìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ Abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré tó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò tí ó tó àádọ́jọ. Òun náà sì ti ṣe olóòtú sinimá àgbéléwò tó tó mẹ́rìnlá.
'''Ìyábọ́ Alice Òjó''' (tí a bí ní Ọjọ́ kọnkànlélógún oṣù Kejìlá ọdún 1977)jẹ́ òṣèrébìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ Abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré tó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò tí ó tó àádọ́jọ. Òun náà sì ti ṣe olóòtú sinimá àgbéléwò tó tó mẹ́rìnlá. <ref name="Austine Media 2018">{{cite web | title=Iyabo Ojo Biography and Net Worth - Austine Media | website=Austine Media | date=2018-04-13 | url=https://austinemedia.com/iyabo-ojo-biography-and-net-worth/ | access-date=2019-11-26}}</ref>


Ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́
Ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́


Gẹ́gẹ́ bí a ṣe sọ ṣáájú, wọ́n bí Ìyábọ́ Òjó lọ́jọ́ kọnkànlélógún oṣù Kejìlá ọdún 1977. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ọmọ Abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ Ògùn ni bàbá rẹ̀, Ìlú Èkó ni wọ́n bí i sí. Ó kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní Gbàgágà nílùú Èkó, ó kàwé ní National College ní Gbàgágà kó tó tẹ̀ síwájú ní ní ilé ìwé gíga Polí ti ìpínlẹ̀ Èkó, Lagos State Polytechnic níbi tí ó ti gboyè nínú imọ̀ ètò ìkọlé, (Estate Management)
Gẹ́gẹ́ bí a ṣe sọ ṣáájú, wọ́n bí Ìyábọ́ Òjó lọ́jọ́ kọnkànlélógún oṣù Kejìlá ọdún 1977. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ọmọ Abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ Ògùn ni bàbá rẹ̀, Ìlú Èkó ni wọ́n bí i sí. Ó kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní Gbàgágà nílùú Èkó, ó kàwé ní National College ní Gbàgágà kó tó tẹ̀ síwájú ní ní ilé ìwé gíga Polí ti ìpínlẹ̀ Èkó, Lagos State Polytechnic níbi tí ó ti gboyè nínú imọ̀ ètò ìkọlé, (Estate Management)<ref name="BBC News Yorùbá 2019">{{cite web | title=Òótọ́ ni Iyabo Ojo ń sọ́! Ìdójútì gbàá ni kí Òṣèré máa tọrọ owó tórí àìsàn - Femi Adebayo | website=BBC News Yorùbá | date=2019-10-08 | url=https://www.bbc.com/yoruba/49975377 | language=la | access-date=2019-11-26}}</ref>


Akitiyan rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré
Akitiyan rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré


Ìyábọ́ Òjó tí kópa nínú sinimá àgbéléwò tó tó àádọ́jọ. Láti ìgbà èwe rẹ̀, pàápàá jùlọ ní ilé ẹ̀kọ́. Lọ́dún 1998 ló bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà ní ṣàn-án. Ọ̀rẹ́ rẹ̀ kan, Bím̀bọ́ Akíntọ̀lá ló ràn án lọ́wọ́ láti dára pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèré tíátà, (the Actors Guild of Nigeria)
Ìyábọ́ Òjó tí kópa nínú sinimá àgbéléwò tó tó àádọ́jọ. Láti ìgbà èwe rẹ̀, pàápàá jùlọ ní ilé ẹ̀kọ́. Lọ́dún 1998 ló bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà ní ṣàn-án. Ọ̀rẹ́ rẹ̀ kan, Bím̀bọ́ Akíntọ̀lá ló ràn án lọ́wọ́ láti dára pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèré tíátà, (the Actors Guild of Nigeria). Ìyábọ́ Òjó kì í ṣe òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá nìkan, ó máa ń kópa nínú sinimá àgbéléwò ti èdè òyìnbó bákan náà. Lọ́dún 1998, ó kópa nínú eré èdè òyìnbó kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Satanic". "Baba Dáríjìnwọ́n" ni sinimá àgbéléwò rẹ̀ àkókò lédè Yorùbá lọ́dún 2002. Lẹ́yìn èyí, ó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò tó pọ̀ súa. Ìyábọ́ Òjó tí lọ́kọ, ó sìn tí sabiyamọ. <ref name="Pulse Nigeria 2017">{{cite web | title=Photos from actress' daughter's sweet 16 party | website=Pulse Nigeria | date=2017-03-13 | url=https://www.pulse.ng/entertainment/celebrities/iyabo-ojo-photos-from-actress-daughters-sweet-16-party/lz8nyjc | access-date=2019-11-26}}</ref> <ref name="Okogba Okogba 2019">{{cite web | last=Okogba | first=Emmanuel | last2=Okogba | first2=Emmanuel | title=Iyabo Ojo debunks rumours she never married, releases marriage photos.. | website=Vanguard News | date=2019-06-09 | url=https://www.vanguardngr.com/2019/06/iyabo-ojo-debunks-rumours-she-never-married-releases-marriage-photos-certificate/ | access-date=2019-11-26}}</ref> <ref name="The Nation Newspaper 2019">{{cite web | title=Iyabo Ojo’s daughter becomes brand ambassador - The Nation Newspaper | website=The Nation Newspaper | date=2019-06-22 | url=https://thenationonlineng.net/iyabo-ojos-daughter-becomes-brand-ambassador/ | language=la | access-date=2019-11-26}}</ref>


==Àwọn Ìtọ́kasí==
Career Edit
{{Reflist}}
Having been involved in a drama group at secondary school, Iyabo Ojo commenced her acting career in 1998. She registered with the Actors Guild of Nigeria (AGN) through the help of Bimbo Akintola, she was also able to network to other people [7]

Ojo has scripted and featured in several Nigerian films. Her first role was in 1998's Satanic, an English-language film. In 2002, she made her Yoruba-language debut with Baba Darijinwon.[8] In January 2015, her film Silence, which features Joseph Benjamin Alex Usifo, Fathia Balogun, and Doris Simeon, premiered at the Silverbird Cinemas, Ikeja, in Lagos.[9][10]

In 2004, Ojo started producing her own films. Ojo's first production wass Bolutife, after which she made Bofeboko, Ololufe, Esan and Okunkun Biribiri.[1]

Àtúnyẹ̀wò ní 07:52, 26 Oṣù Bélú 2019

Ìyábọ́ Alice Òjó (tí a bí ní Ọjọ́ kọnkànlélógún oṣù Kejìlá ọdún 1977)jẹ́ òṣèrébìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ Abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré tó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò tí ó tó àádọ́jọ. Òun náà sì ti ṣe olóòtú sinimá àgbéléwò tó tó mẹ́rìnlá. [1]

Ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́

Gẹ́gẹ́ bí a ṣe sọ ṣáájú, wọ́n bí Ìyábọ́ Òjó lọ́jọ́ kọnkànlélógún oṣù Kejìlá ọdún 1977. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ọmọ Abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ Ògùn ni bàbá rẹ̀, Ìlú Èkó ni wọ́n bí i sí. Ó kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní Gbàgágà nílùú Èkó, ó kàwé ní National College ní Gbàgágà kó tó tẹ̀ síwájú ní ní ilé ìwé gíga Polí ti ìpínlẹ̀ Èkó, Lagos State Polytechnic níbi tí ó ti gboyè nínú imọ̀ ètò ìkọlé, (Estate Management)[2]

Akitiyan rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré

Ìyábọ́ Òjó tí kópa nínú sinimá àgbéléwò tó tó àádọ́jọ. Láti ìgbà èwe rẹ̀, pàápàá jùlọ ní ilé ẹ̀kọ́. Lọ́dún 1998 ló bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà ní ṣàn-án. Ọ̀rẹ́ rẹ̀ kan, Bím̀bọ́ Akíntọ̀lá ló ràn án lọ́wọ́ láti dára pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèré tíátà, (the Actors Guild of Nigeria). Ìyábọ́ Òjó kì í ṣe òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá nìkan, ó máa ń kópa nínú sinimá àgbéléwò ti èdè òyìnbó bákan náà. Lọ́dún 1998, ó kópa nínú eré èdè òyìnbó kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Satanic". "Baba Dáríjìnwọ́n" ni sinimá àgbéléwò rẹ̀ àkókò lédè Yorùbá lọ́dún 2002. Lẹ́yìn èyí, ó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò tó pọ̀ súa. Ìyábọ́ Òjó tí lọ́kọ, ó sìn tí sabiyamọ. [3] [4] [5]

Àwọn Ìtọ́kasí

  1. "Iyabo Ojo Biography and Net Worth - Austine Media". Austine Media. 2018-04-13. Retrieved 2019-11-26. 
  2. "Òótọ́ ni Iyabo Ojo ń sọ́! Ìdójútì gbàá ni kí Òṣèré máa tọrọ owó tórí àìsàn - Femi Adebayo". BBC News Yorùbá (in Èdè Latini). 2019-10-08. Retrieved 2019-11-26. 
  3. "Photos from actress' daughter's sweet 16 party". Pulse Nigeria. 2017-03-13. Retrieved 2019-11-26. 
  4. Okogba, Emmanuel; Okogba, Emmanuel (2019-06-09). "Iyabo Ojo debunks rumours she never married, releases marriage photos..". Vanguard News. Retrieved 2019-11-26. 
  5. "Iyabo Ojo’s daughter becomes brand ambassador - The Nation Newspaper". The Nation Newspaper (in Èdè Latini). 2019-06-22. Retrieved 2019-11-26.