Àdàkọ:Ayoka Ose/42

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Genevieve Nnaji (pípè /n'nɑːdʒɪ/, ọjọ́ìbí May 3, 1979 ní Mbaise, Ipinle Imo, Nigeria), jẹ́ òṣèré filmu ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà. Ní 2005 ó gba Ẹ̀bùn Akadẹ́mì Filmu ilẹ̀ Áfríkà gẹ́gẹ́ bíi Òṣèré Obìnrin Tódárajùlọ.Ìlú Èkó ni Genevieve Nnaji ti dàgbà.

Ìkẹrin nínú àwọn ọmọ méjọ, ọ̀mọ̀wé ni àwọn òbí rẹ̀. Bàbá rẹ̀ siṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi onímọ̀ iṣẹ́-ẹ̀rọ (engineer) nígbàtí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ olùkọ́. Ò lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Methodist Girls College ní Yaba, lẹ́yìn rẹ̀ ó tẹrísí Yunifásítì ìlú Èkó. Níbẹ̀ lówà tó ti bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣiṣẹ́ díèdíẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré ni Nollywood. (Ekunrere...)