Àfin Al-Gawhara

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Al-Gawhara Palace (Lárúbáwá: قصر الجوهرةQaṣr al-Gawhara), jẹ́ àfin àti musíọ́mùCairo, Egypt. Àfin náà wà ní gúúsù Mọ́sálásíi Muhammad AliCairo Citadel. Muhammad Ali Pasha ni ó ṣe àfilọ́lẹ̀ ní ọdún 1814.

Àwọn àkọ́lé láti oríṣiríṣi orílẹ̀ èdè bi Gríkì, Turks, Bulgaria àti Albania ni ó kọ.[1]:17 Ní ọdún

In 1822, iná ba apá kan àfin náà jẹ́, iná yẹn jó fún ọjọ́ méjì, àwọn ibi tí ó sì bàjẹ́ jẹ́ àwọn ibi tí a fi pákọ́ ṣe, Muhammad padà fe ilé náà nígbà tí ó kó apá míràn mọ, wọ́n fi ìṣàn omi, òdòdó àti àwọn míràn tings."[1]

Lẹ́yìn ọdún méjì, ní ọdún 1824, iná tún ba àfin náà jẹ́. Muhammad Ali sì tún tun ṣe.[1]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 Johnston, Shirley. Egyptian Palaces and Villas. New York: Abrams. ISBN 0-8109-5538-5.  Photographs by Sherif Sonbol