Àmì-ìdámọ̀ kẹ́míkà
Appearance
Àmì-ìdámọ̀ kẹ́míkà jẹ́ lẹ́tà -1 tàbí -2 tó jẹ àmì ọ̀rọ̀ tí wọ́n tẹwọgba káríayé fún àpilẹ̀ṣẹ̀ kẹ́míkà kan, lọ́pọ̀ ìgbà tó ń wà láti orúkọ àpilẹ̀ṣẹ̀ náà, nígbà púpo ni Latini. Lẹ́tà àkọkọ́ nìkan ni ó jẹ́ nlá. Fún àpẹẹrẹ, "He" ni àmì-ìdámọ̀ fún hiliom (English name, not known in ancient Roman times), "Pb" for lead (plumbum in Latin), "W" for tungsten (wolfram in German, not known in Roman times). Temporary symbols assigned to newly or not-yet synthesized elements use 3-letter symbols. For example, "Uno" was the temporary symbol for Hassium which had the temporary name of Unniloctium.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |