Jump to content

Àmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Nàìjíríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Nàìjíríà
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ọ̀pá àṣẹNàìjíríà
MottoUnity and Faith, Peace and Progress

Àmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ Nàìjíríà ni asa dudu pelu ila funfun meji ti won tenu po bi Y. Awon wonyi duro fun odo nla meji ni Naijiria: Odò Benue ati Odò Niger.