Àsìá ilẹ̀ Guatẹmálà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
National flag. Flag ratio: (5:8)
Civil flag and ensign. Flag ratio: (5:8)

Asia ile Guatemala ni awo meji: bulu sanmo ati funfun. Awon ila bulu sanmo mejeji duro fun idie pe Guatemala budo si aarin okun meji, Okun Pasifiki ati Okun Atlantiki (Omi-okun Karibeani); ati awo sanmo oju orile-ede na (e wo Orin Iyin Orile-ede Guatemala). Awo funfun tokasi alafia ati ogidi.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]