Àsìá ilẹ̀ Trínídád àti Tòbágò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
National flag (used as state and military flag). Flag ratio: 3:5

Àsìá orile-ede Trínídád àti Tòbágò je gbigba fun lilo nigba ti o gba ilominira lowo Britani Olokiki ni 31 August 1962.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]