Àtòjọ àwọn àwọn ilé-iṣẹ́ tó tóbi jùlọ Ní Nigeria
Ìrísí
Èyí ni àtòjọ àwọn ilé-iṣẹ́ tó tóbi jùlọ ní Nigeria nípa bí wọ́n ṣe ń powó sí àti owó ìdókowò wọn títí di ọdún 2024, gẹgẹ bí ìfisípò àwọn ilé-iṣẹ́ 500 tó tóbi jùlọ ní Africa tí Jeune Afrique àti African Business. Ó tó ọgbọ́n nínú 500 àwọn ilé-iṣẹ́ tó tóbi jùlọ Ní Africa nípa owó tí wọ́n ń pa wọlé ló wà ní Nigeria.
Nípa iye owó tí wọ́n pa wọlé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn wọ̀nyí ni mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n àwọn ilé-iṣẹ́ tó tóbi jùlọ (láìsí ilé-ìfowópamọ́) nípa iye owó tí wọ́n ń pa wọlé lọ́dún 2022 (pàápàá jùlọ fún ìsúná-owó ọdún 2021).[1]
Ipò | Ilé-iṣẹ́ | Ẹ̀yà ilé-iṣẹ́ | Iye owó tí wọ́n ń pa wọlé ní (US$ millions) |
Èrè tí wọ́n ń jẹ ní (US$ millions) |
---|---|---|---|---|
1 | Nigeria National Petroleum | Oil and gas | 9,706 | 1,877 |
2 | Nigeria Liquefied Natural Gas | Oil and gas | 6,315 | ... |
3 | MTN Nigeria | Telecommunications | 3,514 | 536 |
4 | Dangote Cement | Cement | 2,699 | 721 |
5 | Nigerian Petroleum Development | Oil and gas | 2,686 | 219 |
6 | Flour Mills of Nigeria | Agroindustry | 2,014 | 67 |
7 | Airtel Nigeria | Telecommunications | 1,503 | 343 |
8 | Nigerian Breweries | Agroindustry | 890 | 19 |
9 | Jumia | Retail | 837 | ... |
10 | Nestle Nigeria | Agroindustry | 749 | 102 |
11 | Krystal Digital Network Solutions | Infotech | 678 | 21 |
12 | Julius Berger | Construction | 631 | 3 |
13 | Nigerian Bottling Company | Agroindustry | 627 | ... |
14 | Lafarge Africa | Cement | 602 | 97 |
15 | Dangote Sugar Refinery | Agroindustry | 559 | 78 |
16 | BUA Cement | Cement | 547 | 184 |
17 | TotalEnergies Nigeria | Oil and gas | 534 | 5 |
18 | Seplat Petroleum Development | Oil and gas | 498 | −80 |
19 | Ardova Plc | Oil and gas | 474 | 5 |
20 | 11PLC | Oil and gas | 428 | 16 |
21 | International Breweries plc | Agroindustry | 357 | −32 |
22 | Conoil | Oil and gas | 307 | ... |
23 | Honeywell Flour Mill | Agroindustry | 286 | 3 |
24 | PZ Cussons Nigeria | Consumer goods | 216 | 4 |
25 | UAC of Nigeria | Conglomerate | 213 | 11 |
Nípa iye owó ìdókowò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ilé-iṣẹ́ tó tóbi jùlọ ogún nípa iye owó ìdókowò wọn lọ́dún 2022.[2]
Ipò | Ilé-iṣẹ́ | Ẹ̀yà ilé-iṣẹ́ | Iye owó ìdókowò ní (US$ millions) |
---|---|---|---|
1 | Dangote Cement | Cement | 11,203 |
2 | MTN Nigeria | Telecommunications | 10,471 |
3 | Airtel Nigeria | Telecommunications | 6,903 |
4 | BUA Cement | Cement | 5,759 |
5 | Nestle Nigeria | Agroindustry | 2,658 |
6 | BUA Foods | Agroindustry | 2,575 |
7 | Zenith Bank | Banking | 1,691 |
8 | Guaranty Trust Holding Company PLC | Finance | 1,585 |
9 | First Bank of Nigeria | Banking | 1,070 |
10 | Stanbic IBTC Holdings | Finance | 1,064 |
11 | Lafarge Africa | Cement | 918 |
12 | Access Holdings | Finance | 833 |
13 | Nigerian Breweries | Agroindustry | 890 |
14 | United Bank for Africa | Finance | 633 |
15 | Ecobank | Banking | 529 |
16 | Dangote Sugar Refinery | Agroindustry | 467 |
17 | Union Bank of Nigeria | Banking | 431 |
18 | Guinness Nigeria | Consumer goods | 375 |
19 | Okomu Oil Palm | Agroindustry | 343 |
20 | Presco PLC | Agroindustry | 320 |
Ẹ wò yí náà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- List of companies of Nigeria
- List of largest companies by revenue
- List of largest companies in Africa by revenue
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Classement 2022 des 500 premières entreprises africaines : le palmarès complet - Jeune Afrique.com". JeuneAfrique.com (in Èdè Faransé). Retrieved 2024-01-28.
- ↑ "Africa’s Top 250 Companies, 2022". African Business (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-05-09. Retrieved 2024-01-28.