Jump to content

Union Bank of Nigeria

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Union Bank of Nigeria
TypePublic Company
Founded1917
Headquarters36 Marina, Lagos Island, Lagos, Lagos State, Nigeria
Key peopleMr. Farouk Gumel
Chairman
Mr. Mudassir Amray
Chief Executive Officer
IndustryFinancial services
ProductsLoans, Target Savings, UnionMobile, Agency Banking
Total assetsUS$6.3 billion (NGN2,793 billion) (2022)
Employees2200
Websiteunionbankng.com

Union Bank of Nigeria Plc jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ilé-ìfowópamọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà, tí olú-ilé-iṣé rẹ̀ wà ní Victoria Island, Lagos. Ó ti ń ṣiṣẹ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, láti ọdún 1917.[1]


Union Bank jẹ́ ilé-ìfowópamọ́ ńlá, tó ń ṣiṣẹ́ fún àwọn ènìyàn, ilé-iṣẹ́ kékeré àti alábọ́dé, pẹ̀lú àwon ilé-iṣẹ́ ńlá. Ní oṣù keje ọdún 2009, wón tò ó pọ̀ sí ipò 556th, ìyẹn mọ́ àwọn ilé-ìfowópamọ́ tó tóbi jù lọ ní àgbáyé, àti sí ipò kẹrìnlá, ìyẹn sára àwọn ilé-ìfowópamọ́ tó tóbi jù lọ ní ilẹ̀ Africa.[2] Títí di ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kẹta, ọdún 2018, gbogbo dúkìá ilé-ìfowópamọ́ náà ń lọ bí i NGN1,381 bílíọ́ọ̀nù (US$ 4.1billion). Owó tí ó kan àwọn tí ọ̀rọ̀ kàn nínuh ilé-ìfowópamọ́ náà ń lọ NGN286 bílíọ́ọ̀nù (US$ 851 million).[3]

 

Àwòrán ilé-iṣẹ́ ti Union Bank tí ó wà ní Port Harcourt .

A lè tọ́ka ìtàn ilé-ìfowópamọ́ yìi sí ọdún 1836 nígbà tí àwọn òṣìṣẹ́ báǹkì ìlú London àti onísòwò ilẹl Britani gba ìwé àéhùn ọlọ́lá lahti ọwọ́ Wiliam IV láti máa ṣàkóso ètò ìṣòwol báǹkì ní Caribbean. Ẹgbé àwọn olùdókòwò yìí sì ṣèdásílẹ̀ Colonial Bank.Látàri òfin tí iléìgbìmọ̀ aṣòfin gbé kalẹl pé àwọn ilé-ìfowópamọ́ le ń ẹ̀ka ilé-iṣẹ́ káàkiri Caribbean àti lẹ́yìn odi, Colonial bank wá bẹ̀rè iṣẹ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ní ọdún 1917. Isé náà bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú dídá ilé-iṣẹ́ sí Ìpínlẹ̀ Èkó, Jos àti Port Harcourt.[4] Wọ́n ṣí àwọn ẹ̀ka mìíràn sílẹ̀, ní ọdún 1918, ní Ebute Metta, Onitsha, Ìbàdàn, Kano, àti Zaria, wọ́n sì tún dá òmítàn sílẹ̀ ní Burutu, ní ọdún 1921.[5]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Union Bank, firm lift 6,000 local farmers". The Punch newspaper. Retrieved 29 September 2022. 
  2. "Union Bank Emerges Winner At The Middle East & Africa Innovation Awards". Tribune newspaper. Retrieved 25 April 2022. 
  3. "Nigeria: Standard Chartered Group, Others Buy 65 Percent Stake in Union Bank". http://allafrica.com/stories/201210300247.html. Retrieved 2017-08-29. 
  4. "Union Bank unveils upgraded branches in Port Harcourt". Guardian newspaper. Archived from the original on 15 September 2016. Retrieved 14 September 2016. 
  5. Union Bank Bounces Back. Yaba, Lagos: VBO International Ltd.