Àwọn Ìkún omi Accra ní ọdún 2022

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìkún omi dé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ibi ní Accra ní ìgbà òjò

Ní ọjọ́ Kàrún oṣù kéfa ọdún 2022 tí ó bọ́ sí ọjọ́ ìsinmi, ìkún omi ya wọ àwọn apá ibì kan ní ìlú ìpínlẹ̀ Accra lẹ́yìn ìgbà tí òjò rọ́ọ̀.[1] Òjò náà tí ó rọ̀ fún wákàtí mẹrin ba àwọn jẹ́ ní agbègbè bi Kaneshie.

Àwọn ibòmíràn tí ìkún omi tún yawọ̀ ni Kwame Nkrumah Circle, Spintex Road, Tetteh Quarshe, Fiesta Royal àti Nsawam Road.[2]

Nítorí ìkún omi tí ó ṣẹlẹ̀ ní Accra, ààrẹ Akufo-Addo darí àwọn District Assemblies (MMDAs) in the Greater Accra Region láti wó gbogbo ǹkan tí ó wà lọ́nà omi náà, eléyìí sì fa ìkún omi ní àwọn ìlú.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Parts of Accra flooded again after downpour". Citinewsroom - Comprehensive News in Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-06-05. Retrieved 2022-07-25. 
  2. "Parts of Accra flooded again, social media users react". GhanaWeb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-07-05. Archived from the original on 2022-07-25. Retrieved 2022-07-25. 
  3. "Parts of Accra flooded again after downpour". Citinewsroom - Comprehensive News in Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-06-05. Retrieved 2022-07-25.