Àwọn èdè ní Áfríkà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán àfiwé àwọn èdè tí wọ́n ń sọ ní Áfríkà

Ìye àwọn èdè tí wọ́n so ní Áfríkà lé ní ẹgbẹ̀rún méjì,[1] kódà àwọn míràn sọ wípé ó lé ní ẹgbẹ̀rún mẹ́ta.[2] Nàìjíríà nìkan ní tó èdè ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta,(gẹ́gẹ́ bí SIL Ethnologue) ṣe fi léde,[3] Áfríkà jẹ́ ara àwọn ilẹ̀ tí oríṣiríṣi àwọn èdè pò sí jù. Àwọn èdè Áfríkà wá láti oríṣiríṣi ìdílé èdè, àwọn bi:

Àwọn èdè kéékèèké míràn wà tí wọn kò tí ì sì nínú ìdílé kan kan. Àwọn èdè kọ̀kan tún wà ní ilẹ̀ Áfríkà tí wón jẹ́ èdè tí ọ̀pọ̀lopọ̀ àwọn ẹ̀yà ń sọ. Àwọn èdè bi Arabic, Somali, Amharic, Oromo, Igbo, Swahili, Hausa, Manding, Fàtini.

Ààjọ African Union kéde ọdún 2006 gẹ́gẹ́ bi "Ọdún àwọn èdè Áfríkà".[4].


Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Heine, Bernd; Heine, Bernd, eds (2000). African Languages: an Introduction. Cambridge University Press. 
  2. Epstein, Edmund L.; Kole, Robert, eds (1998). The Language of African Literature. Africa World Press. p. ix. ISBN 0-86543-534-0. https://books.google.com/books?id=XkkrDH27jmIC&pg=PR9. Retrieved 2011-06-23. "Africa is incredibly rich in language—over 3,000 indigenous languages by some counts, and many creoles, pidgins, and lingua francas." 
  3. "Ethnologue report for Nigeria". Ethnologue Languages of the World. 
  4. African Union Summit 2006 Archived 30 May 2006 at the Wayback Machine. Khartoum, Sudan. SARPN.