Àwọn ènìyàn Efik
Ìrísí
Àpapọ̀ iye oníbùgbé | |||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
1 million+[1] | |||||||||
Regions with significant populations | |||||||||
Nigeria, Cameroon | |||||||||
| |||||||||
Èdè | |||||||||
Ẹ̀sìn | |||||||||
Ẹ̀yà abínibí bíbátan | |||||||||
Ibibio, Annang, Akamkpa, Eket, Ejagham (or Ekoi), Bahumono, Oron, Biase, Uruan, Igbo, Bamileke. |
Àwọn ènìyàn Efik jẹ́ ẹ̀yà tí ó wà ní apá gúúsù Nàìjíríà, àti apá ìwọ̀ òórùn Cameroon. Ní Nàìjíríà, a lè rí àwọn ẹ̀yà Efik ní ibi tí ó jẹ́ Ìpínlẹ̀ Cross River àti Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom lóde òní. Èdè àwọn ènìyàn Efik ni Èdè Efik tí ó jé ọkàn lára àwọn ìdílé èdè Benue–Congo tí àkójọ èdè Niger-Congo.[5] Àwọn ènìyàn Efik ma ń pe ara wọn ní Efik Eburutu, Ifa Ibom, Eburutu àti Iboku.[6][7]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Joshua Project – Efik of Nigeria Ethnic People Profile
- ↑ "Efik in Nigeria". Joshua Project (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved November 13, 2019.
- ↑ "Efik in Cameroon". Joshua Project (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved November 13, 2019.
- ↑ "Efik in USA". Joshua Project (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved November 13, 2019.
- ↑ Faraclas, p.41
- ↑ Simmons, p.11
- ↑ Amaku, p.2