Àwọn ẹ̀yà Xhosa
Appearance
Àpapọ̀ iye oníbùgbé | ||||||
---|---|---|---|---|---|---|
8,104,752 (2011 Census) | ||||||
Regions with significant populations | ||||||
| ||||||
Èdè | ||||||
Ẹ̀sìn | ||||||
Ẹ̀yà abínibí bíbátan | ||||||
Zulu, Hlubi, Swati and Southern and Northern Ndebele people |
Àwọn ẹ̀yà Xhosa ( /ˈkɔːsə,_ˈkoʊsə/;[2][3] Àdàkọ:IPA-xh) (pípè ní Yorùbá bíi Kósà) ni ẹ̀ka ẹ̀ya àwọn Bantu tó búdò sí Apágúúsù Áfríkà àgàgà ní Eastern Cape. Àwọn ẹ̀yà Xhosa kékeré (Mfengu) tún wà ní Zimbabwe, níbi tí èdè wọn, isiXhosa, ti jẹ́ gbígbà bíi èdè ọmọ orílẹ̀-èdè.[4]
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Hlenze Welsh Kunju, 2017 Isixhosa Ulwimi Lwabantu Abangesosininzi eZimbabwe: Ukuphila Nokulondolozwa Kwaso, PhD Dissertation, Rhodes University.
- ↑ "Xhosa – pronunciation of Xhosa". Macmillan Dictionary. Macmillan Publishers Limited. Retrieved 16 April 2014.
- ↑ Laurie Bauer, 2007, The Linguistics Student's Handbook, Edinburgh
- ↑ Nombembe, Caciswa. "Music-making of the Xhosa diasporic community: a focus on the Umguyo tradition in Zimbabwe." Masters dissertation, School of Arts, Faculty of Humanities, University of the Witwatersrand, 2013.