Jump to content

Áárọ́nì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Áárọ́nì

Nínú Bíbélì, Áárọ́nì ni ègbón Mósè. Òun ni ó se èkejì Móósè gégé bí olórí fún àwon ara Isiréélì nígbà tí wón n la aginjù kojá tí wón n lo sí ilè ìlérí láti Íjíbíìtì. Wón n lo sí ilè ìlérí Kénáànì. Òun ni ó se èrè àgùntàn onígóòlù fún won. Ó kú ní orí òkè Hor nígba tí ó di omo odún métàlélógófà.