Èbúté-Èrò
Ìrísí
Èbúté-Èrò | |
---|---|
Town | |
Ebute-Ero street, showing Tram" Lines (between 1910 and 1913) | |
Coordinates: 6°27′47″N 3°23′15″E / 6.46306°N 3.38750°ECoordinates: 6°27′47″N 3°23′15″E / 6.46306°N 3.38750°E | |
Country | Nigeria |
State | Ìpínlẹ̀ Èkó |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
Ebúté Èrò jẹ́ ìlú kan tí ó wà ní abẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ Lagos Island ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà .[1] Èbúté Èrò jẹ́ ìlú ńlá tí ó gbajúmọ̀, tí ó sì gbèrò ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Èbúté Èrò jẹ́ òkùn tí ó so àwọn ọmọ Ìpínlẹ̀ Èkó ayé àtijọ́ pọ̀ mọ́ ayé òde òní, Ọjà ìlú náà ni ó sì jẹ́ ọjà tí ó tóbi jùlọ nínú àwọn ọjà tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó àti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2][3][4]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Whiteman, Kaye (21 October 2013). Lagos. ISBN 9781908493897. https://books.google.com/books?id=fcS_BAAAQBAJ&q=Ebute+Ero+Street,+Lagos+State&pg=PT73. Retrieved 26 April 2015.
- ↑ The Oxford Encyclopedia of Economic History. 2003. ISBN 9780195105070. https://books.google.com/books?id=ssNMAgAAQBAJ&q=Ebute+Ero+Market+lagos&pg=RA4-PA462. Retrieved 26 April 2015.
- ↑ Udo, Reuben K. (1970). "Geographical Regions of Nigeria". google.co.uk. Retrieved 26 April 2015.
- ↑ Mobile Transactions Architecture: Lagos---rethinking the Drive Through Market. ISBN 9781109213461. https://books.google.com/books?id=rGS5g9TzIzwC&q=Ebute+Ero+Market+lagos&pg=PA8. Retrieved 26 April 2015.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]