Èdè Àmháríkì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Amharic
አማርኛ amarəñña
Ìpè /amarɨɲɲa/
Sísọ ní  Ethiopia
 Ẹritrẹ́à
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ 25,000,000+ total, 15,000,000+ monolinguals (1998)
Èdè ìbátan
Sístẹ́mù ìkọ Ge'ez alphabet abugida
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Èdè oníbiṣẹ́ ní Ethiopia and the following specific regions: Addis Ababa City Council, Amhara Region, Benishangul-Gumuz Region, Dire Dawa Administrative council, Gambela Region, SNNPR
Àkóso lọ́wọ́ no official regulation
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1 am
ISO 639-2 amh
ISO 639-3 amh

Amhariki Èdè Sèmítíìkì (Semitic) kan ni eléyìí tí nnkan bú mílíònu márùndínlógún ń so gégé bí èdè àkókó ní Ethopia (ìtópíà). Níbè, wón ń lò ó gégé bí tí ìjoba ń mú lò. Àwon bú mílíònù márùn-ún ni ó ń so èdè yìí ní agbègbè Ethiopia nígbà tí  àwon òpòlopò mílíònù mìíràn ń so èdè yìí gégé bí èdè kejì àkókúntenu ní Ethiopia àti Sudan (Sùdáànù). Láti nnkan bíi séńtúrì kerìnlá (14th Century) ni èdè yìí ti ní àkosílè. Àkotó Amharic ni wón fi ko ó sílè. Àkotó yìí ní Kóńsónántì métàlélógbòn òkòòkan won sì ní èdà méjeméje. Èdà kóńsónántì tí ènìyàn yóò mú lò dúró lóró fáwèlì tí kóńsónántì náà yóò bá je yo. Àbá ti ń wáyé nípa pé kí àtúnse wà fún àkotó yìí. Àwon kan sì ti kóra won jo fún ìpolongo láti so èdè yìí di àjùmòlò (Standardisc).


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]