Èdè Abkhaz
Ìrísí
Abkhaz | |
---|---|
Аҧсуа бызшәа; аҧсшәа | |
Sísọ ní | Turkey, Russia, Georgia, Jordan, Syria, Iraq Abkhazia (Recognized as independent by Russia, Nauru, Nicaragua, and Venezuela) |
Agbègbè | Caucasia |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | 125 000 |
Èdè ìbátan | |
Sístẹ́mù ìkọ | Abkhaz alphabet |
Lílò bíi oníbiṣẹ́ | |
Àkóso lọ́wọ́ | Kòsí àkóso oníbiṣẹ́ |
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-1 | ab |
ISO 639-2 | abk |
ISO 639-3 | abk |
Èdè kan ni eléyìí lára àwọn èdè tí a ń pè ní Abkhazo-Adyghian tí àwọn wọ̀nyí tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ fún àkójọpọ̀ èdè tí a ń pè ní caucasian (Kọ̀kọ́síànù). Àwọn tí ó ń sọ Abkhaz tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọ́rùn-ún ènìyàn ní ìpínlẹ̀ tí a ń pè ní Abkhaz ní Georgia. Ó wà lára àwọn èdè ti ìjọba ń lò níbẹ̀. Wọ́n tún ń sọ èdè yìí ní apá kan ilẹ̀ Tọ́kì (Turkey).
àkọtọ́ Cyrillic (Sìríhìkì) ni wọ́n fi ń kọ èdè yìí sílẹ̀.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |