Èdè Bijago

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Bijago
Sísọ ní Guinea-Bissau
Agbègbè Offshore Bissagos Islands
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ 30,000
Èdè ìbátan
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-3 bjg

Èdè Bijago tabi Bidyogo jé okan pàtàkì lára àwon orisìírísìí èdè bí i méédógbòn tí wón ń so láti ile Guinea-Bissau, orúko mìíràn tí a tún mo èdè yìí sí ni: Bigogo, Byougout. Bijuga, Budjago, Bugago. Bákan náà ni a mò wón mo àwon. Èka Èdè bíi: Anhaki, kagbaaga, Kajoko, Kamona àti Orango wópò nínú èdè Bidgogo.

Gbogbo àwon èdè náà ni won sì tì ń so títí di àkókò yìí. Àwon Niger-Congo tó jé eya Bijago ló máa ń so èdè náà.