Jump to content

Ìbejì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwọn ìbejì tó jọra

Àwọn Ìbejì jẹ́ àwọn ọmọ méjì tí ìyá wọn lóyún papọ̀, wọ́n lè jẹ́ obìnrin meji, ọkùnrin méjì tàbi ọkùnrin kan àti obìnrin kan. Àwọn ìbejì le ti àti inú ẹyin kan jade tàbí láti inú ẹyin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀.[1] Àwọn tí ó jáde láti inú ẹyin kan ma ń jo ara wọn, wọ́n sì ma ń jẹ́ ọkùnrin méjì tàbí obìnrin méjì. Ní igbamiran(ìṣẹ̀lẹ̀ yí kò wọ́pọ̀), àwọn ìbejì kan le ní baba méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀.

Ní gbogbo àgbáyé, ẹ̀yà Yoruba ni àwọn ọmọ wọn ń ya ìbejì jù, àwọn ìbejì 45 sí 50(àwọn ọmọ 90 sí 100) ni ó ń ya ìbejì nínú gbogbo ọmọ ẹgbẹ̀rún tí wọ́n bá bí.[2][3][4]

  1. Michael R. Cummings, 5-7 Twin Studies and Complex Traits in "Human Heredity Principles and issues" p. 104.
  2. Zach, Terence; Arun K Pramanik; Susannah P Ford (2007-10-02). "Multiple Births"Free registration required. WebMD. Retrieved 2008-09-29. 
  3. "Genetics or yams in the Land of Twins?". Independent Online. 2007-11-12. https://www.iol.co.za/news/africa/genetics-or-yams-in-the-land-of-twins-378435. 
  4. "The Land of Twins". BBC World Service. 2001-06-07. https://www.bbc.co.uk/worldservice/people/highlights/010607_twins.shtml.