Ìgbà Ààrẹ Umaru Musa Yar'Adua

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ìgbà Ààrẹ Umaru Musa Yar'Adua bere ni 29 May, 2007 leyin ayeye ibura gege bi Aare orile-ede Naijiria ketala. Ki Yar'Adua o to di Aare o ti koko je Gomina Ipinle Katsina lati 1999 de 2007. Ninu idiboyan to waye ni April 21, 2007 Yar'Adua lo bori pelu ibo 24.6 legbegberun to je 70% awon ibo didi si 6.6 legbegberun ti Muhammadu Buhari to je olutako re julo. Sibesibe awon olutako oniselu pe idiboyan ohun ni ojoro won si bere fun ifagile re.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]