Ìgbẹ́ Ènìyàn
Ìgbẹ́ Ènìyàn tàbí Imí jẹ́ àwọn ohun óúnjẹ tí a jẹ tí ó dà àmọ́ tì kò dà tán nínú ikùn tàbí agbẹ̀du ènìyàn.[1][2] Ìgbẹ́ ma ń ní àwọn èròjà àìfojúrí tí wọ́n ń pè ní (bacteria), (biliribin) ati díẹ̀ (epithelial) nínú àwon sẹ́ẹ̀lì tí wọ́n ti kú,[1] lẹ̀yìn tí yóò sì jáde láti ẹnu ihò-ìdí, tí a ó sì ma pèé ní Ìgbẹ́ nígbà tí a bá yàá sílẹ̀ tán
Ìjọra àwọn ìgbẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìgbẹ́ ọmọnìyàn ma ń fara jọ imí tàbí ìgbẹ́ àwọn ẹranko mìíràn pẹ̀lú ìrísí wọn pẹ̀lú àwọ̀, líle tàbí rírọ̀ ní ìbámu pẹ̀lú ohun tí wọ́n bá jẹ. Ìgbẹ́ ọmọnìyàn ma ń sábà ní ohun bí ikun tabí kẹ̀lẹ̀bẹ̀ tàbí omi lára láti lè jẹ́ kí ó rọrùn bí bá fẹ́ jáde lẹnu ihò-ídí. Wọ́n sàbà m ń lo ìbẹ̀rẹ̀ púpọ̀ jùlọ nínú àwọn àkọsílẹ̀ oríṣiríṣi.[3] Imí àti ìtọ̀ ma ń sábà ń ní à kọ́wọ̀ọ́-rìn lásìkò tí a bá fẹ́ ṣe gá, àwọn méjèjì yí ni wọ́n jẹ́ ẹ̀gbin ọmọnìyàn tó lágbára jùlọ.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Tortora, Gerard J.; Anagnostakos, Nicholas P. (1987). Principles of anatomy and physiology (Fifth ed.). New York: Harper & Row, Publishers. p. 624. ISBN 978-0-06-350729-6. https://archive.org/details/principlesofan1987tort.
- ↑ Diem, K.; Lentner, C. (1970). "Faeces". in: Scientific Tables (Seventh ed.). Basle, Switzerland: CIBA-GEIGY Ltd.. pp. 657–60.
- ↑ "Stool".