Ìjàmbá ìtúká ẹ̀búté Bèírùtù ọdún 2020
![]() Aftermath of the explosions, showing the destroyed grain silo to the left and the flooded blast crater to the right | |
![]() | |
Date | 4 Oṣù Kẹjọ 2020 |
---|---|
Time | 18:08:18 EEST (15:08:18 UTC) (second explosion) |
Venue | Port of Beirut |
Location | Beirut, Lebanon |
Coordinates | 33°54′05″N 35°31′08″E / 33.90139°N 35.51889°ECoordinates: 33°54′05″N 35°31′08″E / 33.90139°N 35.51889°E |
Type | Ammonium nitrate explosion |
Cause | Fire |
Deaths | 207+ |
Non-fatal injuries | 6,500+ |
Missing | 9 |
Property damage | US$15+ billion |
Displaced | ~300,000 |
Ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kẹrin oṣù kẹjọ ọdún 2020, àwọn ìjàmbá ìtúká aláriwo olóró méjì ṣẹlẹ̀ ní èbúté ìlú Bèírùtù, tó jẹ́ olúìlú orílẹ̀-èdè Lẹ́bánọ́nù. Ìtúká aláriwo kejì lágbára tó bẹ́ẹ̀ tó, ó fa ikú àwọn ènìyàn tó pọ̀ tó 207, ìpalára àwọn ènìyàn tó tó ẹgbẹ̀fàlélẹ́ẹ̀dẹ́gbẹ̀ta, ìbàjẹ́ àwọn ohun ìní tí iye owó wọn tó US$10–15 billionu, ó sì sọ àwọn ènìyàn tó pọ̀ tó 300,000 di aláìnílé.[1]Ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ṣẹlẹ̀ nítorí 2,750 tonnes (3,030 short tons; 2,710 long tons) àmóníọ́mù onínáítrójínì – tí agbára rẹ̀ tó 1.2 kilotons of TNT (5.0 TJ) – tí ìjọba Lẹ́bánọ́nù ti gbẹ́sẹ̀lé látọwọ́ ọkọ̀ ojú-omi akẹ́rù "MV Rhosus", tí wọ́n sì kó pamọ́ sí apá kan ní èbúté náà láì sí àbò àti ìṣọ́ra tó yẹ fún ọdún mẹ́fà.
Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ "Infographic: How big was the Beirut explosion?". Al Jazeera. 2022-08-04. Retrieved 2023-08-30.