Ìjígbé àwọ̀n ọmọ ilé ìwé Chibok
Ní oru ọjọ́ kẹrìnlá sí kẹ̀ẹ́dọ́gún ọdún 2014, àwọn ìkọ̀ ogun Boko Haram jí àwọn ọmọ obìnrin ẹ̀rin dín ní ọ́rin-lé-nígba(279) gbé ní Government Girls School ní ìlú Chibok, Ìpínlẹ̀ Bornu, Nàìjíríà. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ tí wọ́n jí gbé jẹ́ Krìstẹ́nì.[1][2][3] Kí ikọ̀ náà tó ya wo ilé ìwé náà, wọ́n ti ti ilé ìwé náà fún ọ̀sẹ̀ mẹ́rin nítorí ìbẹ̀rù nípa ètò àbò, ṣùgbọ́n àwọn ọmọ ilé ìwé náà wá ilé ìwé láti wá kọ ìdánwò wọn nínú ìmọ̀ physics.
Mẹ́tàdínlógójì nínú àwọn ọmọ náà yọ bó lọ́wọ́ àwọn ikọ̀ náà nípa fífò jábọ́ nínú ọkọ̀ tí wọ́n fi kó wọn, àwọn Ọmọ ogun Nàìjíríà rí àwọn kan gbà padà.[4][5] Àwọn míràn gbàgbọ́ pé wọ́n sì ma tú àwọn ọmọ náà sílẹ̀, àwọn míràn sì gbàgbọ́ pé díè nínú àwọn ọmọ tí wọ́n jí gbé ti sọ ẹ̀mí wọn nù.[6] Wọ́n rí Amina Ali, ọkàn lára àwọn ọmọ tí wọ́n jí gbé ní oṣù Kàrún ọdún 2016. Ó ní àwọn ọmọ tó kù wà nínú ìhámọ́ ikọ̀ náà, ṣùgbọ́n mẹ́fà ti kú nínú wọn.[7] Ní oṣù kẹrin ọdún 2021, ọdún méje lẹ́yìn ìgbà tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà sè, àwọn ọmọ tí ó lé ní ọgọ́rùn-ún ni ó sì sọnù.[8][9][10]
Àwọn Ìtọ́kaṣí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "US names Nigeria's Boko Haram and Ansaru 'terrorists'" (in en-GB). BBC News. 13 November 2013. https://www.bbc.com/news/world-africa-24931684.
- ↑ "88 Nigerian schoolgirls abducted by Islamic extremists still missing". The Guardian. Associated Press. 19 April 2014. https://www.theguardian.com/world/2014/apr/19/88-nigerian-schoolgirls-abducted-by-islamic-extremists-still-missing.
- ↑ Omeni, Akali (11 April 2017). "The Chibok Kidnappings in North-East Nigeria: A Military Analysis of Before and After". Small Wars Journal 14 (4). https://smallwarsjournal.com/jrnl/art/the-chibok-kidnappings-in-north-east-nigeria-a-military-analysis-of-before-and-after. Retrieved 18 November 2017.
- ↑ Romo, Vanessa (21 February 2018). "Nigerian Military Rescues 76 Schoolgirls After Alleged Boko Haram Attack". NPR (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 26 October 2020. Retrieved 23 October 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Smith, Alexander; Bratu, Becky (20 May 2016). "Another Schoolgirl Taken by Boko Haram Is Rescued, Nigerian Army Says". NBC News. https://www.nbcnews.com/storyline/missing-nigeria-schoolgirls/another-schoolgirl-taken-boko-haram-rescued-nigerian-army-says-n577216.
- ↑ Strochlic, Nina (March 2020). "Six years ago, Boko Haram kidnapped 276 schoolgirls. Where are they now?". National Geographic Society. Archived from the original on 21 April 2021. Retrieved 21 April 2021. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Boko Haram abductees freed in Nigeria". BBC News. 20 May 2016. https://www.bbc.com/news/world-africa-36338989.
- ↑ "Nigeria: 7 years after Chibok mass abduction, still no solution". Al Jazeera. 21 April 2021. https://www.aljazeera.com/news/2021/4/14/nigeria-7-years-after-chibok-mass-abduction-still-no-solution.
- ↑ Obiezu, Timothy (15 April 2021). "More Than 100 Chibok Girls Still Missing Seven Years Later". Voice of America. https://www.voanews.com/africa/more-100-chibok-girls-still-missing-seven-years-later.
- ↑ "Nigeria: Seven years since Chibok, the government fails to protect children". Amnesty International (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 14 April 2021. Archived from the original on 17 April 2021. Retrieved 18 April 2021. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)