Ìjọba Iwo
Ìrísí
Iwo Kingdom | |
---|---|
Coordinates: 7°38′N 4°11′E / 7.633°N 4.183°ECoordinates: 7°38′N 4°11′E / 7.633°N 4.183°E | |
Country | Nàìjíríà |
State | Ìpínlẹ̀ Osun |
Ijoba iwó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Ìbílẹ̀ àtijọ́ ní ìlú Iwo ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Nàìjíríà. Ìjọba Yoruba náà, tí orúkọ ọba rẹ̀ jẹ́ "Oluwo of Iwo", ti wà láti ṣẹ́ńtúrì kẹrìnlá.[1]
Gẹ́gẹ́ bí ó ti wà nínú ìtàn, àwọn ènìyàn Iwo wá láti Ile-Ife nibi ti wọ́n ti kó wá sí Iwó ní Ṣẹ́ntúrì kẹrìnlá.[1] Wọ́n dá ìlú tí ó jẹ́ ìlú Iwó lọ́wọ́lọ́wọ́ kalẹ̀ láàrin ṣẹ́ńtúrì kẹrindínlógún sí ìkẹtàdínlógún.[2]
Àwọn Ọba
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìbẹ̀rẹ̀ ìjọba won | Ìparí ìjọba wọn | Oba |
---|---|---|
1415 | 1505 | Parin |
1505 | 1541 | Olayilumi |
1550 | 1610 | Adegunodo |
1610 | 1673 | Olufate Gbase |
1673 | 1744 | Alawusa |
1744 | 1816 | Ogunmakinde |
1816 | 1906 | Monmodu Ayinla Lamuye |
1906 | 1909 | Sunmonu Osunwo |
1909 | 1929 | Sanni Alabi Abimbola Lamuye |
1929 | 1930 | Seidu Adubiaran Lamuye |
1930 | 1939 | Abanikanda Amuda Akande |
1939 | 1952 | Kosiru Ande Lamuye |
1953 | 1957 | Raifu Ajani Adegoroye |
1958 | 1982 | Samuel Omotoso Abimbola |
1992 | 2013 | Asiru Olatunbosun Tadese |
2015 | present | Abdulrasheed Adewale Akanbi |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "History". Iwoland. Archived from the original on 2011-05-30. Retrieved 2010-09-26.
- ↑ "History and traditions of Iwo". Encyclopædia Britannica. http://www.britannica.com/EBchecked/topic/427953/oluwo. Retrieved 2010-09-26.