Jump to content

Ìkónilẹ́rú ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Slavery

Ìkónilẹ́rú ti fi ara hàn ní gbogbo ọ̀nà káàkiri gbogbo ìtàn Nàìjiríà. ó fara hàn jùlọ ni àsìkò òwò-ẹrú Atlantic àti òwò-ẹrú-Saharan.[1][2] Òwò-ẹrú tí di ohun tí ó lòdì sí òfin báyìí kárí-ayé àti ní orílè-èdè Nìgéríà pàápàá.[2] Ní orílè-èdè Nàìjíríà, àwọn ìṣe, àti ẹ̀ṣìn tí ṣokùfa àìlèdẹkun ìtànká láàárín ìṣe, ìṣẹ̀ṣe àti àwọn ìṣe ẹ̀sìn pẹ̀lú àwọn aṣòfin orílẹ̀-èdè ní ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè Áfríkà èyí sì fún wọn ní agbára láti fi ipá ní àkóso tí kò sí òfin tó dè wọ́n lórí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn èèyàn èyí tí ó di ìkónilẹ́rú ní ayé-òde òní.[3] Ìkónilẹ́rú tó wọ́pọ̀ jùlọ ni orílẹ-ẹ̀dè Nàìjíríà ni kíkó àwọn ènìyàn ní ọ̀nà tí kò ní ẹ̀tọ́ àti fífí ọmọdé-ṣerú[2] Nítorí pé ó ṣòro láti dá òwò-ẹrú tí ìgbàlódé mọ̀, ó ṣòro láti gbógun ti ìṣe yìí bí ó tilẹ̀ jẹ́pé àwọn orílẹ̀-èdè káàkiri àgbáyé ń sapá láti fi òpin si.[2]

Ìtàn òwò-ẹrú ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Òwò-ẹrú ní apá Gúsù Nàìjíríà ni ó ṣáájú ipa tí àwọn òyìnbó[4] ó sì tẹ̀síwáju lábẹ́lẹ̀ lẹ́yìn tí òpin tí débá òwò-ẹrú ní ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè mìíràn.[5] Nígbà tí òwò-ẹrú gígbé kọjá omi Atlantic dé, àwọn tó ṣe òwò-ẹrú ní apá gúsù mọ́ ìlà-oòrùn Nàìjíríà bẹ̀rẹ̀ sí ní ta ẹrú fún àwọn òyìnbó.[6] Bí ó tilẹ̀ jẹ́pé àwọn alákòóso àwọn ilè Britain ti fi òpin sí òwò-ẹrú lábéélẹ̀ ní àárín 1880,[7] wọ́n fí ààyè gbà á dáadáa títí wọ1930s,[8] òpìn sí dé bàá pátápátá ní ọdún 1940s.[9]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Modern slavery: Nigeria ranks highest in Africa". 23 August 2018. 
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named auto5
  3. Sarich, J., Olivier, M., & Bales, K. (2016). Forced marriage, slavery, and plural legal systems: An african example. Human Rights Quarterly, 38(2), 450-476,542-544.
  4. Nwaubani, Adaobi Tricia (2020-07-19). "'My Nigerian great-grandfather sold slaves'" (in en-GB). BBC News. https://www.bbc.com/news/world-africa-53444752. 
  5. Nwaubani, Adaobi Tricia (July 15, 2018). "My Great-Grandfather, the Nigerian Slave-Trader" (in en-us). The New Yorker. https://www.newyorker.com/culture/personal-history/my-great-grandfather-the-nigerian-slave-trader. Retrieved 2020-07-19. 
  6. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :22
  7. Afigbo, A. E. (Adiele Eberechukwu) (2006). The abolition of the slave trade in southeastern Nigeria, 1885-1950. Rochester, NY: University of Rochester Press. ISBN 978-1-58046-668-4. OCLC 256735611. https://www.worldcat.org/oclc/256735611. 
  8. Northrup, David (September 2007). "A. E. Afigbo. The Abolition of the Slave Trade in Southeastern Nigeria. 1885-1950. Rochester: University of Rochester Press, 2006. Rochester Studies in African History and the Diaspora. xv + 210 pp. Maps. Appendixes. Bibliography. Index. $75.00. Cloth." (in en). African Studies Review 50 (2): 228–229. doi:10.1353/arw.2007.0116. ISSN 0002-0206. https://www.cambridge.org/core/product/identifier/S0002020600001165/type/journal_article. 
  9. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :02