Ìlù Ògìdìgbó
Àgídìgbo jẹ́ ohun èlò orin ìbílẹ̀ tí ìrísí rẹ̀ dàbí dùrù (Piano) àwọn Gẹ̀ẹ́sì àwọn Yorùbá tí wọ́n ma ń fi okùn sí láti lè gbe kọ́rùn fún lílù. Lásìkò tí wọ́n bá fẹ̀ dára wọn lára yá. Alágìídìgbo náà yóò wọ òrùka tó lúpọn, ọrùn ìṣà tábí ìgò sọ́wọ́ àtànpàkò rẹ̀, 3yí tí yóò fi ma kan ẹ̀gbẹ pátákó àgídìgbo náà. Yóò sì tún ma fi ọwọ́ mẹ́wẹ̀wá rẹ̀ ta àwọn ìtàkùn ahọ́n irin tí wọ́n ti so mọ́ àpótí àgídìgbo náà lẹ́sẹẹsẹ, tí ìyẹn náà yóò sì ma móhùn àdídùn jáde. Ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ ni wọ́n fi ma ń gbe àgídìgbo lẹ́sẹ̀ lójú aré.[1]
Irúfẹ́ Orin tí ó ń lo Àgídìgbo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n ma ń lo àgídìgbo nínú orin Wákà tàbí Àpàlà. Bákan náà ni àgídìgbo jẹ́ gbajú gbajà khun èlò orin ní àwọn agbègbè bíi Ìbàdàn, Ìjẹ̀bú. Babatunde Yusuf Olatunji, ni ẹni tójẹ́ ìlú-mọ̀ọ́ka olórin tó ma ń lo àgídìgbo nínú orin rẹ̀, pàá pàá jùlọ nínú àwo rẹ̀ tí ó péní "Oyin Mọmọ Àdò" (Sweet as Honey), tí fọ́nrán rẹ̀ sì jẹ́ ẹlẹ́keeje (track 7) ní ọdún 1959.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "[ARCHIVE] Custom Jutsu Submission - II". Anime Forum. 2012-02-24. Retrieved 2019-12-28.