Jump to content

Ìmọ̀ àjàkálẹ̀-àrùn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ìmọ̀ àjàkálẹ̀-àrùn ni ẹ̀kọ́ àti ọ̀nà ìgbékalẹ̀ àti ìgbéyẹ̀wò bí àrùn ṣe ń tàn kálẹ̀ láàrín àwọn ènìyàn. Ó tún jẹ́ ọ̀nà (ìwádìí àrùn), àti ohun ń fa àjàkálẹ̀ àrùn. Ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ilé-iṣẹ́ ìjọba tó ń mójútó ìbẹ́sílẹ̀ àjákálẹ̀-àrùn ni Nigeria Centre for Disease Control.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]