Jump to content

Ìpínlẹ̀ Gòngólà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ipinle Gongola.

Ipinle Gongola jẹ́ ìpínlẹ̀ ìjọba ní Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ kí ó tó di pínpín sí Ìpínlẹ̀ Tàrábà àti Ìpínlẹ̀ Àdámáwá ní ọdún 1991. Ó jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọjọ́ kẹta Oṣù kejì ọdún 1976 lati ìgbèríko Àdámáwá àti Sàdáunà ní Ìpínlẹ̀ Àríwá-Apáìlàọrùn.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Gongola State of Nigeria Executive Council". Library of Congress Pamphlet Collection - Flickr. Retrieved 2014-05-11. 

Coordinates: 8°30′N 11°45′E / 8.500°N 11.750°E / 8.500; 11.750