Jump to content

Ìrànwọ́:Báwo lẹṣe le dá ojúewé tuntun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ọ̀ nà méjì ló wà láti bẹ̀rẹ̀ ojúewé tuntun.

  • Bí ẹ bá fẹ́ dá àkòrí tàbí àyọkà kan sí orí Wikipedia Yorùbá, ẹ kọ àkòrí ọ̀rọ̀ náà sí inú 'apótí ìṣàwárí' kí ẹ sì tẹ Ṣàwárí. Bí ohun tí ẹ béèrè bá ti jẹ́ dídá sí orí Wikipedia tẹ́lẹ̀, akọ́lé náà yóò wá ní awọ Búlúù, amọ́ tí kò bá yì tiì sí ní orí ìkanì Yorùbá Wikipedia, yóò wá ní awọ̀ pupa. Bí ó bá wá ní àwọ̀ pupa ẹ má bẹ̀rù, Wikipedia fẹ́ kí ẹ ṣẹ̀dá irúfẹ́ akọ́lé bèẹ̀ ni.
  • ṣe ìjápọ̀ inú lòri ojúewé kan fún àkọlé ọ̀rọ̀ tí kò ṣí, ìjápọ̀ náá yíò jẹ́ lẹ́tà pupa. Tí ẹ bá tẹ klik lórí rẹ̀, yíò mu yín lọ́ sí ààyè "Àtúnṣe sí" àkọlẹ́ ọ̀rọ̀ òfọ pẹ̀lú orúkọ ìjápọ̀ náà, níbẹ̀ ni ẹ ti lè kọ ìkọ àkọlé ọ̀rọ̀ náà. Tí ẹ bá ṣe tán ẹ tẹ bọ́tìnì "Ìmúpamọ́ ojúewé" tó wà lábẹ́ ààyè náà láti fi ojúewé tuntun náà pamọ́.
  • Bí ẹ bá fẹ́ bẹ̀rẹ̀ àkọ́lé ọ̀rọ̀ tuntun èyí tí kò sí nínú Wikipedia tẹ́lẹ̀, ẹ kọ àkọ́lé rẹ̀ sínú àpótí "Ṣàwárí" tó wà ní apá ọ̀tún ojúewé (lábẹ́ Àwọn àfikún tí ó wà ní òkè ní apá ọ̀tún ojúewé). Kí ẹ sì tẹ Ṣàwárí . Tí àkọlé ọ̀rọ̀ náà bá wà lórí Wikipedia tẹ́lẹ̀ , yíò gbà yín ní ààyè láti ṣàtúnṣe rẹ̀, sùgbọ́n tí kò bá sí, àkọ́lé tí ẹ ṣàwárí rẹ̀ yóò wà ní awọ̀ pupa. Ẹ tẹ akọ́lẹ́ pupa náà, tí yíò mu yín lọ sí ààyè tí ẹ ti lè ṣe "Ṣẹ̀dá" àyọkà náà, bó ṣe jẹ́ fún ti àkọ́kọ́.

Fún àwọn ìlànà ìkọ̀wé, ẹ wo Wikipedia:Ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ àti ìlànà ìgbékalẹ̀ àyọkà. Bákanáà ẹ tún wo ìkìlọ̀ fún Wikipedia.