Jump to content

Ìsẹ́yìn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ìséyìn)
Ìsẹ́yìn
Ilu
Nickname(s): 
Ilu Aso Oke
Orílẹ̀-èdè Nigeria
IpinleOyo
Agbegbe Ijoba IbileIseyin
Population
 • Total256,926
Websitehttp://www.iseyinland.com
Ìtàn ṣókí nípa Iseyin láti ẹnu ọmọ bíbí ìlú Iseyin
Iseyin

Iseyin-Okeogun
LGA and town
Nickname(s): 
Iseyin oro, oro ọmọ ebedi mọkọ
Iseyin is located in Nigeria
Iseyin
Iseyin
Coordinates: 7°58′N 3°36′E / 7.967°N 3.600°E / 7.967; 3.600
Country Nigeria
StateOyo State
Government
 • Local Government Chairman and the Head of the Local Government CouncilMuftau Osuolale (PDP)
Area
 • Total548 sq mi (1,419 km2)
Time zoneUTC+1 (WAT)
ClimateAw
Short Oral history of Iseyin in Onko Language by a native speaker

Ìsẹ́yìn jẹ́ ìlú kan tó wà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́Nàìjíríà. Tí a lè It wí pé ó wà ní apá Àríwá Ìbàdàn. Ìlú náà ni ènìyàn bí i 236,000, gẹ́gẹ́ bí United Nations ṣe sọ ní 2005, tí àwọn ènìyàn yìí di 362,990 ní ọdún 2011,[1] [2] Ìsẹ́yìn jẹ́ ibí tó jẹ́ wí pé a lè dé ibí tí a bá gba ọ̀nà Ìbàdàn, Ọ̀yọ́, Abẹ́òkúta àti Ògbómọ̀sọ. Ìlú náà ni ilẹ̀ tó fẹ̀, tó ṣe é fi ṣe ilé-òwò àti dá oko, ilé-ìwé fún àǹfààní ní àti àyíká ìlú náà. Orúkọ ọba tí ó jẹ́ ní Isẹ́yìn ni " Àsẹ́yìn Ìlú Ìsẹ́yìn". Àwọn ilé-ìwé pọ̀ ní Ìsẹ́yìn, lára wọn ni Ládòkè Akíntólá, Politẹ́kíníkì bí SAF Politẹ́kíníkì, Ilé-ìwé sẹ́kọ́ndárí bí Kelani Kọlẹ̀jì Ìsẹ́yìn, Greater Love Model àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Tó wà ní àkọsílẹ̀ wí pé àwọn ilé-ìwé yìí ń ṣe dáadáa ní àwọn ìdánwò bí WASSCE & SSCE.

Àwọn ìlúmọ̀ọ́ká tó wá láti Ìsẹ́yìn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Díẹ̀ nínú àwọn ìlúmọ̀ọ́ká tó wá láti Ìsẹ́yìn ni:

Professor Peller

Olukayode Ariwoola

Shina Peller


Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. National Population Commission of Nigeria (web)
  2. Adewuyi, Kehinde; Adeyemo; Adejumo (December 2018). "Use of GIS in production of soil series map in Oyo State, southwestern Nigeria". International Research Journal of Earth Sciences 6 (12): 12–21. ISSN 2321-2527. http://www.isca.me/EARTH_SCI/Archive/v6/i12/2.ISCA-IRJES-2018-019.pdf. 

Coordinates: 7°58′N 3°36′E / 7.967°N 3.600°E / 7.967; 3.600