Jump to content

Ìtúká onítítànyindin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìtúká álfà jẹ́ àpẹrẹ kan irú is one example type of ìtúká títànyindin, nibi ti nukleu atomu kan ti tu alfa alaratintinni kan sita, bi bayi to yirapada (tabi 'tuka') di atomu to din ni nomba akojo 4 ati to din ni nomba atomu 2. Orisi iru ituka miran lo tun se e se.

Ìtúká onítítànyindin tabi ítuka titanyindin tabi ituka radioaktifu ni igbese nibi ti nukleu atomu kan ti atomu ti ko ni iduro lese pofo okun-inu nipa yiyojade awon alaratintinni toun je sisodi ioni (iranka ijeonisisodiioni|). Awon orisirisi iru ituka titanyindin lowa. Ituka, tabi ipofo okun-inu, unsele nigbati atomu kan to ni iru nukleu kan, to unje radionuklidi obi, yirapada di atomu to ni nukleu kan ni ipoaye to yato, tabi to di nukleu oto to ni iye proton ati neutron oto. Eyi to wu ninu awon yi ni o unje nuklidi omo. Ninu awon ituka miran obi ati omo je elimenti kemika otooto, nitori eyi igbese ituka fa iyirapada nukleu wa (ida atomu elimenti tuntun).


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]