Ìwàìbàjẹ́
Ìrísí
Ìwàìbàjẹ́ olóṣèlú tabi ìwàìbàjẹ́ lasan ni lilo agbara sisofin àwon onise ijoba fun ere adani lona to lodi sofin. Ko si iru ìjọba ti ko le se iwaibaje oloselu. Iru iwabaje jorisirisi, sugbon won mupo mo gbigba abetele, ituje, isojusaju, isojuebi, agbaje, afunje, ati ikowoje.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |