Jump to content

Ìyìnbọn mọ́ ọ̀pọ̀ ènìyàn ní ṣọ́ọ̀sì ní Charleston

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìyìnbọn mọ́ ènìyàn ní ṣọ́ọ̀sì Charleston
A white-painted church at sunset.
LocationEmanuel African Methodist Episcopal Church
Charleston, South Carolina, U.S.
Coordinates32°47′15″N 79°55′59″W / 32.78750°N 79.93306°W / 32.78750; -79.93306Coordinates: 32°47′15″N 79°55′59″W / 32.78750°N 79.93306°W / 32.78750; -79.93306
DateOṣù Kẹfà 17, 2015 (2015-06-17)
c. 9:05 p.m. – c. 9:11 p.m.[1] (EDT)
TargetAfrican American churchgoers
Attack typeMass shooting[2]
Hate crime
Weapon(s)Glock 41 .45-caliber handgun
Death(s)9[2][3]
Injured1[4]
BelligerentDylann Roof (sentenced to death)[5]

Ìyìnbọn mọ́ ọ̀pọ̀ ènìyàn ní ṣọ́ọ̀sì ní Charleston (tí a tún mọ̀ bi Ìfikúparun ṣọ́ọ̀sì ní Charleston) jẹ́ ìṣẹ́lẹ̀ ìfìbọn pa ọ̀pọ̀ èníyàn tó ṣẹlẹ̀ nígbàtí Dylann Roof, tó jẹ́ oníṣègbéraga àwọn aláwọ̀funfun ọmọ ọdún 21 fìbọn pa àwọn aláwọ̀dúdú ará Amẹ́ríkà mẹ́sàn (tí olùṣọ́-àgùtàn àgbà àti, alàgbà ilé aṣòfin Clementa C. Pinckney wà nínú wọn) nígbà tí wọ́n únṣe ìsìn àdúrà nínú Ṣọ́ọ̀ṣì Emanuel African Methodist Episcopal ni ilu Charleston, South Carolina, ni ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ 17 oṣù kẹrin, ọdún 2015. Awọn mẹ́ta péré ló yè nínú àwọn tó yìnbọn mọ́. Ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì tó ṣe iṣẹ́ ibi rẹ̀ tán, àwọn ọlọ́ọ̀pá gbá Roof mú ní Shelby, North Carolina. Roof jẹ́wọ́ iṣẹ́ ibi tó ṣe nírètí pé yíò fa ogun ẹlẹ́yàmẹ̀yà wá. Ṣọ́ọ̀ṣì tí Roof ti lọ pa àwọn ènìyàn ló jẹ́ ìkan núnú àwọn ṣọ́ọ̀ṣì aláwọ̀dúdú tó dàgbàjùlọ ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, tó jẹ́ ibùdó fún àgbájọ àwùjọ nípa àwọn ẹ̀tọ́ aráàlú.

Wọ́n pinu pé Roof le dúró fún ìgbẹ́jọ́ ní ilé-ẹjọ́ ìjọba àpapọ̀, ni Oṣù Kejìlá ọdún 2016 wọ́n dá Roof lẹ́bi ẹ̀sùn 33 tí wọ́n jẹ́ ọ̀ran ikorira lábẹ́ ìjọba àpapọ̀ àti ẹ̀sùn ìpànìyàn tó ṣe pẹ̀lu ìyìnbọn náà. Ní ọjọ́ 10 Oṣù Kínní, ọdún 2017, wọ́n dá ẹjọ́ iku fun. [6] Lọ́tọ̀ Roof ní ẹ̀sùn ọ̀ràn ìpànìyàn mẹ́sàn ní ilé-ẹjọ́ ìpínlẹ̀ South Carolina. Ní Oṣù Kẹrin ọdun 2017, Roof gbà pé òhun jẹ̀bi ẹ̀sùn mẹ́sẹ̀ẹ̀sán tí ìjọba ìpínlẹ̀ fi kan kó le baà yẹra fún ìdájọ́ ikú kejì, nítoríẹ̀ wọ́n dá ẹjọ́ ìjùṣẹ̀wọ́n ayérayé fún, fún ìkọ̀ọ̀kan àwọn ẹ̀sùn náà, èyí sínà fún ìjọba àpapọ̀ láti pàṣẹ ikú rẹ̀ nígbà tọ́ bá yá.

Roof fìgbàgbọ́ rẹ̀ hàn nípa ìkóríra ẹlẹ́yàmẹ̀yà nínú manifẹ́stò tó kọ sórí internet kó tó lọ yìnbọn pa àwọn ènìyàn lọ́jọ́ náà, àti nínú ìwé-ìṣẹ̀lẹ̀ tó kọ ní túbú lẹ́yín náà. ẹlẹ ṣaaju ki ibon naa, ati akọsilẹ kan ti a kọ lati ile-ẹhin lẹhinna. Awọn aworan ti a fi sori aaye ayelujara fihan Ọṣọ ti o nmu pẹlu awọn ami-ami ti o ni nkan ṣe pẹlu itẹsiwaju funfun ati pẹlu awọn fọto ti Flag of Confederate. Ibon yiyan ni ijiroro lori ifarahan onibara rẹ, ati tẹle awọn ibon yiyan, South Carolina Gbogbogbo Apejọ dibo lati yọ awọn Flag lati Ipinle Capitol ilẹ.

Awọn tó fikú dá lóró[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awọn tó fikú dá lóró jẹ́ mẹ́sàn, obìnrin mẹ́fà àti okùjrin mẹ́ta tí gbogbo wọ́n jẹ́ ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà ìjọ Methodist. Àwọn mẹ́jọ ku lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ níbẹ̀; ẹni kẹsan, Daniel Simmons, ku ni MUSC Medical Centre. [7] Gbogbo wọn kú pa nipasẹ ọpọlọpọ awọn ibon gunshots ti firanṣẹ ni sunmọ ibiti o. Awọn eniyan marun ti o ye ni ihamọ ti ko ni agbara, pẹlu Felicia Sanders, iya ti o ti pa lẹgbẹ Tywanza Sanders, ati ọmọ-ọmọ ọmọ rẹ marun ọdun, pẹlu Polly Sheppard, ọmọ ẹgbẹ ẹkọ Bibeli kan. Aya iyawo Pinckney ati awọn ọmọbirin meji tun wa ninu ile lakoko ti ibon. Awọn ti o pa ni a mọ bi:

  • Clementa C. Pinckney (41) – wòólì àti alàgbà ilé-aṣòfin South Carolina.
  • Cynthia Marie Graham Hurd (54) – Bible study member and manager for the Charleston County Public Library system; sister of politician and former state senator Malcolm Graham.
  • Susie Jackson (87) – a Bible study and church choir member. She was the oldest victim of the shooting.
  • Ethel Lee Lance (70) – the church's sexton.
  • Depayne Middleton-Doctor (49) – a pastor who was also employed as a school administrator and admissions coordinator at Southern Wesleyan University.
  • Tywanza Sanders (26) – a Bible study member; grandnephew of victim Susie Jackson. He was the youngest victim of the shooting.
  • Daniel L. Simmons (74) – a pastor who also served at Greater Zion AME Church in Awendaw.
  • Sharonda Coleman-Singleton (45) – a pastor; also a speech therapist and track coach at Goose Creek High School; mother of MLB prospect Chris Singleton.
  • Myra Thompson (59) – a Bible study teacher.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]