Òṣèlúaráìlú

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí

Òṣèlú je ijoba oniselu aralu boya to ba wa taara latowo awon aralu tabi won fun awon asoju won lase ninu idiboyan lati lo agbara yi. Ni ede Geesi o n je democracy to wa lati oro ede Griiki: δημοκρατία - (dēmokratía) to tunmo si "agbara aralu"[1] eyi ti won yi wa lati δῆμος (dêmos), "aralu" ati κράτος (krátos) "agbara" larin orundun ikarun-ikerin kJ lati tokasi iru sistemu oniselu to wa nigbana ni awon ilu-orile-ede Grisi, pataki ni Ateni Atijo leyin rogbodiyan odun 508 kJ.
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]