Òṣùpá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Òsùpá

Òsùpá je oluyipo (satellite) ile-aye. Arinidaji jijinnasi lati ile aye titi de ori osupa je 384,403 kilometres. Eyi je ilaarin ona 30 ile-aye. Ilaarin osupa je 3,474 kilometres - to je pe die lo fi ju okan ninu merin lo si ti ile-aye. Eyi si je pe kikuninu (volume) osupa je 1/50th pere ti ile-aye. Fifa iwuwosi re je 1/6th si ti ile-aye. Osupa n yipo ile-aye ni ekan larin ojo 27.3 (ojo metadinlogbon ole ni wakati meta).Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]