Oṣù
Appearance
Osù jemó ìgbà tàbí àkókò tí a n lo ìwé-ìwo ojó fún tí àyípadà rè sì máa n pé bíi ojú ojó tí ó sì farapé bí òsùpá se n sisé. Osù àti òsùpá ní ìbásepò tó dánmórán.
Kí a tólè mo bí osù se n sisé, a gbódò ní òye púpò nípa bí òsùpá se n sisé. Òdiwòn tí òsùpá àti osù fi n sisé kòju "ókàn dín lógbòn sí métà lé láàdóta ojó lo (29.53) days.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |