Jump to content

Ọdún

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Year)
odun

Ọdún kan jẹ́ iye àsìkó tí ó gba pílánẹ̀tì Ilẹ̀-ayé làti fi yípo Òòrùn kà lẹ́ẹ́kan péré. Ní fífàgùn, a leè fi èyí múlẹ̀ fún pílánẹ̀tì yó wù. Bí àpẹẹrẹ: "ọdún Máàsì" kan yí ò jẹ́ àsìkò tí yí ò gba Máàsì láti yípo Òòrùn léèkan.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]