Ọdún

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ọdún kan je iye asiko ti o gba planeti Ilẹ̀-ayé lati fi yipo Òòrùn ka leekan pere. Ni fifagun, a le se mule eyi fun planeti yiowu. Fun apere, "odun Marsi" kan yio je asiko ti yio gba Marsi lati yipo Oorun leekan.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]