Jump to content

Òfin ìṣèfà àgbálá-ayé Newton

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Isiseero ogbologbo

Òfin Kejì Newton
History of classical mechanics · Timeline of classical mechanics
Ọ̀nàìṣiṣẹ́ òfin ìṣèfà àgbàlá-ayé Newton; ojúàmì ìkójọ m1 kan fa ojúàmì ìkójọ m2 míràn mọ́ra pẹ̀lú agbárá F2 kan tó ní ìbámu mọ́ ọ̀pọ̀ àwọn ìkójọ méjéèjì àti ìbámu òdì mọ́ ìlọ́poméjì ìjìnnà (r) tó wà ní àrin wọn. Bóṣewù kí àwọn ìkójọ tàbí ìjìnnà ó jẹ́, ìtóbi àwọn iye |F1| àti |F2| yíò jẹ́ dídọ́gba ní gbogbo ìgbà. G ni gravitational constant.

Òfin ìṣèfà àgbálá-ayé Newton