Òrìṣà Vlekete
Ìrísí
Òrìṣà Vlekete jẹ́ òrìṣà omi-òkun àwọn ẹ̀yà Ògù ní ìlú Àgbádárìgì tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Badagry ní ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ojúbọ òrìṣà yìí wà ní ibi kan ni ìlú náà tí wọ́n ń pè ní Ojúbọ Vlekete, Ojúbọ yìí ni wọ́n fi sọ orúkọ ọjà ẹrú náà tí wọ́n ń pè ní ọjà Vlekete ni Àgbádárìgì. Ọjà Vlekete jẹ́ ọjà ẹrú tó tóbi jù lọ ní ilẹ̀ Áfíríkà. [1] [2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Dioka, L.C. (2001). Lagos and Its Environs. First Academic. ISBN 978-978-34902-5-3. https://books.google.com/books?id=9pUPAQAAMAAJ. Retrieved 2019-11-30.
- ↑ Fadipe, A.S.; Unesco (2000) (in fr). Commerce D'esclaves Et la Civilisation Occidentale À Badagry. Media Ace. ISBN 978-978-33660-3-9. https://books.google.com/books?id=D5UPAQAAMAAJ. Retrieved 2019-11-30.